Dag Hjalmar Agne Carl Hammarskjöld ( Dag Hammarskjöld (ìrànwọ́·ìkéde)) (29 July 1905 – 18 September 1961) je diplomati, onimo oro-okowo ati oludako ara Swidin.
O je Akowe Agba keji Aparapo awon Orile-ede lati April 1953 titi di ojo to se alaisi ninu ijamba baalu ni September 1961. Ohun nikan ni o gba Ebun Alafia Nobel leyin to se alaisi. Bakanna Hammarskjöld nikan na tun ni Akowe Agba U.N. to se alaisi lenu ise.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Wiki Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Dag Hammarskjöld |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Dag Hammarskjöld, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.