Sir Chandrasekhara Venkata Raman, FRS (Tàmil: சந்திரசேகர வெங்கடராமன்) (7 November 1888 – 21 November 1970) je asefisiksi ara India ti ise ni ipa ninu idagba sayensi ni India.
O gba Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì ni 1930 fun iwari pe nigbati itanmole ba gba oju eroja geere, awon melo ninu imole na to je titakuro yio ni iyipada ninu ibuiru (wavelength) won.
Sir Chandrasekhara Venkata Raman, FRS | |
---|---|
Ìbí | Thiruvanaikoil, Tiruchirappalli, Madras Presidency, British India | 7 Oṣù Kọkànlá 1888
Aláìsí | 21 November 1970 Bangalore, Karnataka, India | (ọmọ ọdún 82)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Indian |
Ẹ̀yà | Tamil |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Indian Finance Department Indian Association for the Cultivation of Science Indian Institute of Science |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Madras |
Doctoral students | G. N. Ramachandran |
Ó gbajúmọ̀ fún | Raman effect |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Knight Bachelor (1929) Nobel Prize in Physics (1930) Bharat Ratna (1954) Lenin Peace Prize (1957) |
Religious stance | Hindu |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article C. V. Raman, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.