Ẹ̀bùn Nobel Nínú Físíksì

Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì (Àdàkọ:Lang-sv) je bibun ni ekan lodun latowo Akademy àwon Sayensi Oba Swidin.

O je ikan ninu Ebun Nobel marun ti won je didasile latowo akoole ijogun Alfred Nobel ni 1895 o si unje bibun lati 1901; awon yioku ni Ebun Nobel ninu Kemistri, Ebun Nobel ninu Litireso, Ebun Nobel Alafia, ati Ebun Nobel fun Iwosan. Ebun Nobel ninu Fisiksi akoko je bibun fun Wilhelm Conrad Röntgen, ara Jemani, " fun idamo ise iwofa pataki to ti se nipa iwari àwọn ìranná (tabi ìranná-x tabi x-rays)." Ebun yi unje mimojuto latowo Nobel Foundation beesini won gba kakiri bi ebun oniyijulo ti onimosayensi kan le gba ninu fisiksi. Won unfihan ni Stockholm ni bi ajoyo ododun ni 10 Osu Kejila, to je ajodun iku Nobel. Físíksì

Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì
The Nobel Prize in Physics
Bíbún fún Outstanding contributions in Physics
Látọwọ́ Royal Swedish Academy of Sciences
Orílẹ̀-èdè Sweden
Bíbún láàkọ́kọ́ 1901
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ http://nobelprize.org
Ẹ̀bùn Nobel Nínú Físíksì
Wilhelm Röntgen (1845–1923), the first recipient of the Nobel Prize in Physics.


Itokasi

Tags:

Alfred NobelNobel Peace PrizeNobel PrizeNobel Prize in chemistryNobel Prize in literatureNobel Prize in physiology or medicinePhysicsStockholmWilhelm Conrad Röntgen

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Èdè HúngárìGerman languageNọ́mbàIrakJamaikaGuadeloupeHollywoodOrin hip hopMontserratPeter KropotkinDaniel BernoulliMarcos Pérez JiménezSebastián PiñeraFranki SwítsàlandìÀgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn OlóróAntonio GramsciMartin Luther King, Jr.BohriomuSophocles1 OctoberSchwerinOrílẹ̀-èdè Olómìnira Áràbù SàhráwìGeorge MarshallZdravljicaÌlaòrùn ÁfríkàYoshirō MoriOṣù Kínní 19El Paso.saToni Morrison10 MarchCell (biology)Ìgbà DẹfoníàIfáIstanbulÌgbìmọ̀ Òlímpíkì AkáríayéFacebook.npSali BerishaLúksẹ́mbọ̀rg27 NovemberÀtòjọ àwọn akọ̀ròyìn ilẹ̀ NàìjíríàPòtásíọ̀mùZincFrancis 1k ilẹ̀ FránsìÀdírẹ́ẹ̀sì IPPort-au-PrinceCaliforniumJet LiHavanaTop-level domainKa (pharaoh)Georges J. F. KöhlerÍrẹ́lándì ApáàríwáHenry 4k ilẹ̀ FránsìAristotuluLa bandera blanca y verdeBitcoinGíwá yunifásítìẸ̀rúndúnJuliu Késárì2021Hílíọ̀mùApáìwọ̀orùn SàháràManuel A. OdríaKísẹ́ròNewfoundland àti Labrador🡆 More