Assamese
Ara ẹgbẹ́ ti ìlà-oòrùn àwọn èdè Indo-Aryan (Indo-Aryan languages ni Assamese. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ to mílíọ̀nù mẹ́rìnlá àbọ̀ (14.5 million). Orílẹ̀-èdè Asam ni wọ́n ti ń sọ èdè yìí jù. Ìlà-oòrùn àríwá orílẹ̀-èdè India ni Asam wà. Àwọn tí ó ń sọ èdè Assamese yìí tún wà ní Bhutan àti Bangladesh. Àkọtọ́ Bengah ni wọ́n fi ń kọ Assamese sílẹ̀. Ìbátan sì ni òun àti èdè Bengah:
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Asamiisi, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.