Akọ́dièyàn (primate) (pípè /ˈpraɪmeɪt/, Àdàkọ:USdict) je ikan ninu ito bioloji Awon Akọ́dièyàn tabi Primates (/praɪˈmeɪtiːz/ prī·mā′·tēz; Latin: prime, first rank), ibe na ni prosimians (lamupo mo lemurs, lorises, galagos ati tarsiers ) ati simians (awon obo ati awon aribieyan) wa.
Ti a ba yo awon eniyan kuro ti wo wa ni gbogbo orile Aye opo awon akodieyan ungbe ni ibi olooru tabi ibi olooru die ti awon Amerika, Afrika ati Asia.
Akọ́dièyàn Primates | |
---|---|
Olive Baboon, Papio anubis | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | |
Infraclass: | Eutheria |
Superorder: | Euarchontoglires |
Ìtò: | Àwọn Akọ́dièyàn (Primates) Linnaeus, 1758 |
Families | |
| |
Range of the non-human primates (green) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Akọ́dièyàn, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.