Isiaka Abiola Ajimobi (ojóìbí 16 December 1949-2020) jé olósèlú omo orílè-èdè Naijiria àti gómìnà Ipinle Oyo láti 29 Osù Karun 2011 titi di 2019.
Ó tun jé Alàgbà ni Ile Alagba Asofin Naijiria láti 2003 de 2007.
Isiaka Abiola Adeyemi Ajimobi | |
---|---|
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ | |
In office 29 May 2011 – 29 May 2019 | |
Asíwájú | Christopher Alao-Akala |
Arọ́pò | Oluwaseyi Makinde |
Senator for Oyo South | |
In office May 2003 – May 2007 | |
Asíwájú | Peter Olawuyi |
Arọ́pò | Kamorudeen Adekunle Adedibu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kejìlá 1949 Oja'ba, Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Aláìsí | 25 June 2020 Lagos, Nigeria | (ọmọ ọdún 70)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Abiola Ajimobi, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.