Ẹ̀bùn Nobel

Ẹ̀bùn Nobel (Ẹ̀bùn Nobel ní èdè Gẹ̀̀ẹ́̀si àti Nobelpriset ní ède Sweden Norwegian: Nobelprisen) ní àwọn èbùn odoódún káríayé tí àwọn ìgbìmọ̀ ará Scandinafia ń fún ni fún ìdámọ̀ ìmúlọsíwájú àṣà àti ìmọ̀ ìjìnlẹ̀.

Wọ́n jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1895 latowo ara Sweden onímọ̀ ẹ̀kọ́ ẹ̀lá (kẹ́místri) Alfred Nobel, olúṣé dynamite. Àwọn èbún nínú Fisiksi, Kemistri, Ìwòsàn, Litireso, ati Alafia koko je bibun ni 1901. Ebun Sveriges Riksbank ninu ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ Okòwò ní Ìrántí Alfred Nobel jẹ́ dídìmúlẹ́ látọwọ́ Sveriges Riksbank ní ọdún 1968 ó sí kọ́kọ́ jẹ́ bíbùn ní ọdún 1969. Bótilẹ̀jẹ́pẹ́ èyí kìí ṣe ẹ̀bùn Nobel gangan, ìkéde àti ìfifún ré̀ ń sélẹ̀ nígbà kan náà mọ́ àwọn ẹ̀bùn yókù. Ẹ̀bùn kọ̀ọ̀kan jẹ́ dídámọ̀ ní pàápàá fún iṣé wọn.

Ẹ̀bùn Nobel
The Nobel Prize
Ẹ̀bùn Nobel
Bíbún fún Outstanding contributions in Physics, Chemistry, Literature, Peace, and Physiology or Medicine.

The Sveriges Riksbank Prize in Economic Sciences in Memory of Alfred Nobel, identified with the Nobel Prize, is awarded for outstanding contributions in Economics.
Látọwọ́ Swedish Academy
Royal Swedish Academy of Sciences
Karolinska Institutet
Norwegian Nobel Committee
Orílẹ̀-èdè Sweden, Norway
Bíbún láàkọ́kọ́ 1901
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ http://nobelprize.org


Itokasi

Tags:

Alfred NobelNobel Memorial Prize in Economic SciencesNobel Peace PrizeNobel Prize in ChemistryNobel Prize in LiteratureNobel Prize in PhysicsNobel Prize in Physiology or Medicine

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Louis 13k ilẹ̀ FránsìSinnamon LoveOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Arunachal Pradesh(225273) 2128 P-LKárbọ̀nùSheik Adam Abdullah Al-IloryNọ́mbà átọ̀mùAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ AleiroÌnáwóPotsdamEarthOrúkọ ìdíléNìjẹ̀rYttriumISO 15022TòmátòÌmúrìnEwìISO 639-213 OctoberEugenio MontaleLucie Šafářová1016 Anitra8 MaySamuel Ajayi CrowtherVladimir PutinÌyáSan FranciscoJohn Sparrow David ThompsonIowaÀwọn sáyẹ́nsì àwùjọJulian ApostatItan Ijapa ati AjaNarendra ModiOrílẹ̀-èdè7 NovemberIlà kíkọ nílẹ̀ YorùbáLeadLítíréṣọ̀qi31gAfghanístànAzare26 September6 MayVladimir LeninOṣù Kẹta20 October26 JuneOlusegun MimikoMarseilleOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàMẹ́rkúríù (pálánẹ́tì)Pópù Alexander 2kPópù Jòhánù Páúlù ÈkejìOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀsà Ìgbéyàwó ní ilè Yorùbá21 OctoberNneka EzeigboỌjọ́ ÀìkúGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèẸkún ÌyàwóJersey🡆 More