Ìsopọ̀ kẹ́míkà ni ìfàmọ́ra láàrin àwọn átọ̀mù tó gba ààyè ìdá àwọn kẹ́míkà tí wọ́n ní átọ̀mù méjì tàbí mẹ́ta.
Ìsopọ̀ náà sẹlẹ̀ nítorí agbára ẹlẹktrostátìkì ìfàmọ́ra láàrin àwọn àgbéru olódì, bóyá láàrin àwọn ẹ̀lẹ́ktrọ̀nù àti núkléù, tàbí gẹ́gẹ́bí ìdá ìfàmọ́ra ipoméjì. Agbára àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà jẹ́ orísirísi; àwọn "ìsopọ̀ líle" bíi àjọfagbáradìmú tábí íónì wà àti àwọn "ìsopọ̀ dídẹ̀" bíi ìbáṣepọ̀ ipoméjì sí ipoméjì, agbara ìfọ́nká London àti ìsopọ̀ háídrójìn.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ìsopọ̀ kẹ́míkà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.