Ìye àwọn èdè tí wọ́n so ní Áfríkà lé ní ẹgbẹ̀rún méjì, kódà àwọn míràn sọ wípé ó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta.
Nàìjíríà nìkan ní tó èdè ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta,(gẹ́gẹ́ bí SIL Ethnologue) ṣe fi léde, Áfríkà jẹ́ ara àwọn ilẹ̀ tí oríṣiríṣi àwọn èdè pò sí jù. Àwọn èdè Áfríkà wá láti oríṣiríṣi ìdílé èdè, àwọn bi:
Àwọn èdè kéékèèké míràn wà tí wọn kò tí ì sì nínú ìdílé kan kan. Àwọn èdè kọ̀kan tún wà ní ilẹ̀ Áfríkà tí wón jẹ́ èdè tí ọ̀pọ̀lopọ̀ àwọn ẹ̀yà ń sọ. Àwọn èdè bi Arabic, Somali, Amharic, Oromo, Igbo, Swahili, Hausa, Manding, Fàtini.
Ààjọ African Union kéde ọdún 2006 gẹ́gẹ́ bi "Ọdún àwọn èdè Áfríkà"..
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Àwọn èdè ní Áfríkà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.