Àwọn Èdè Altaic

Awon ede Altaic Àkójọpọ̀ èdè tí ó tó ọgọ́ta tí nǹkan bíi mílíọ̀nù márùn-dínlọ́gọ́fà ènìyàn ń sọ ni a ń pè ní ‘Altaic’.

Wọ́n ń sọ àwọn èdè wọ̀nyí ní Penisula Balkan (Balkan Penisula) ní ìlà-oòrùn àríwá ilẹ̀ Asia. Wọ́n pín àwọn èdè wọ̀nyí sí ẹgbẹ́ Turkic, Mongolian àti Manchus-Tungus. Àkọsílẹ̀ lórí ìbẹ̀rẹ̀ ìdàgbàsókè àwọn èdè yìí kò pọ̀. Àkọsílẹ̀ lórí Turkic wà ní nǹkan bíi sẹ́ńtúrì kẹ́jọ (8th Century) ṣùgbọ́n a kọ̀ mọ nǹkan kan nípa Mongolian ṣáájú sẹ́ńtúrì kẹtàlá (13th Century). Ó tó sẹ́ńtúrì kẹtàdúnlógún (17th Century) kí a tó rí àkọsílẹ̀ kanka nípa Manchu. Ní sẹ́ńtúrì ogún (20th Century), ìgbìyànjú tó ga wáyé láti sọ àwọn èdè yìí di èdè òde òní. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé tí ó wuyì ni ó ń jáde tí a fi àwọn èdè àdúgbò kọ, bí àpẹẹrẹ, Uzbek. Wọ́n tún ṣe àtúnse sí àwọn àkọsílẹ̀ tí ó ti wà tẹ́lẹ̀, bí àpẹẹrẹ Turkish

Altaic
Ìpínká
ìyaoríilẹ̀:
East, North, Central, and West Asia and Eastern Europe
Ìyàsọ́tọ̀:Altaic
Àwọn ìpín-abẹ́:
Turkic
Mongolic
Tungusic
Korean (generally included)
Japonic (generally included)
ISO 639-2 and 639-5:tut



Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO 3166Titun Mẹ́ksíkòUnited Arab EmiratesÀwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró September 11, 2001EpoAkínwùmí Iṣọ̀láISO 14644-4ÌjíptìAmẹ́ríkà LátìnìISO 428SQLPortable Document FormatÌṣọ̀kan Áfríkà2120 TyumeniaWikisourceAlice BradyPonnaRosa LuxemburgFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìJuliu KésárìGeorges ClemenceauFenesuela50 CentCERNKatẹrínì 2k ilẹ̀ Rọ́síàIléNàìjíríàWikipẹ́díà l'édè YorùbáKọ̀nkọ̀TurkmenistanTransnistriaWikimediaIlẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnAtlantaÈdè JavaISO 3166-1ISO 31BelarusMicrosoftÍsráẹ́lìRáràOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Ilẹ̀ ÁfríkàPornhubGloria EstefanBob McGrathTsẹ́kì OlómìniraOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàISO 14644EminemÀtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira àgbáyéISO/IEC 27007Orúkọ YorùbáISO 19439Ìkàrẹ́-AkókoỌjọ́ 18 Oṣù KẹtaÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1988.nuÌsirò StatistikiPópù Benedict 1kÌwo Orí ilẹ̀ ÁfríkàOwe YorubaISO 639-2Richard Nixon🡆 More