Èdè Azerbaijani
Azerbaijani | |
---|---|
Azərbaycan dili (Latin script) Азәрбајҹан дили (Cyrillic script) آذربایجان دیلی (Perso-Arabic script) | |
Ìpè | /azærbajdʒan dili/ |
Sísọ ní | Iran, Azerbaijan Georgia, Jẹ́mánì Russia, Estonia UK USA Uzbekistan Syria Iraq, Turkey, Turkmenistan Ukraine, Canada |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 20-31 million |
Èdè ìbátan | Altaic (controversial)
|
Sístẹ́mù ìkọ | Latin alphabet for North Azeri in Azerbaijan, Perso-Arabic script for South Azeri in Iran, and, formerly, Cyrillic alphabet for North Azeri (Azerbaijani variants) |
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | |
Àkóso lọ́wọ́ | Kòsí àkóso oníbiṣẹ́ |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | az |
ISO 639-2 | aze |
ISO 639-3 | variously: aze – Azerbaijani (generic) azj – North Azerbaijani azb – South Azerbaijani |
Ọmọ ẹgbẹ́ ni èdè yìí jẹ́ fún ẹgbẹ́ èdè tí a ń pè ní Turkic. Ẹgbẹ́ èdè Turkic yìí jẹ́ ọmọ ẹbí Altaic. Àwọn tí ó ń sọ Azerbaijani tó mílíọ̀nù mẹ́rìnlá ní Azerbaijan ní ibi tí wọ́n ti ń lò ó gẹ́gẹ́ bí èdè ìṣe ìjọbi. Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní Turkey, Syria àti Afgloanistan. Wọ́n tún máa ń pe èdè yìí ni Azeri. Àkọtọ́ Cyrillic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní Azerbaijan ṣùgbọ́n àkọtọ́ Arabic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní Iran. Wọ́n fi ojú èdá èdè pín wọn sí Swuthern Azerbaijani) àti Northern Azerbaijani tí mílíọ̀nù méje ènìyàn ń sọ.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Èdè Azerbaijani, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.