Ààrùn Ẹ̀dọ̀ A

Aarun ẹdọ A (tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí àkóràn ààrùn ẹ̀dọ̀) jẹ́ líle ààrùn àkóràn ti ẹ̀dọ̀ tí kòkòrò àkóràn ààrùn ẹ̀dọ̀ A fà (HAV).

Ọ̀pọ̀ iṣẹlẹ̀ ni kòní àwọn ààmì pàápàá ní ara ọmọdé. Àkókò láàrín àkóràn àti àwọn ààmì, lára àwọn tí o ní, jẹ́ láàrín ọ̀sẹ̀ méjì sí mẹ́fà. Bí àwọn ààmì báwà wọn maa ń wà fún ọ̀sẹ̀ mẹ́jọ wọ́n sì lè pẹ̀lú: ìṣu, èébì, ṣíṣunú, ẹran ara pípọ́n, ibà, àti inú dídùn. Láàrin 10-15% àwọn ènìyàn ní ìrirí wíwáyé àwọn ààmì lákókò oṣù mẹ́fà lẹ́hìn àkóràn àkọkọ́. Ààrùn ẹ̀dọ̀ líle kò sábà ń wáyé ní èyí tí ó wọ́pọ̀ láàrín àwọn àgbàlagbà.

Ààrùn ẹ̀dọ̀ A
Ààrùn ẹ̀dọ̀ AÌṣẹlẹ̀ ní èyí tí ààrùn ẹ̀dọ̀ A ńfa ìbà pọ́njú-pọ́njú
Ààrùn ẹ̀dọ̀ AÌṣẹlẹ̀ ní èyí tí ààrùn ẹ̀dọ̀ A ńfa ìbà pọ́njú-pọ́njú
Ìṣẹlẹ̀ ní èyí tí ààrùn ẹ̀dọ̀ A ńfa ìbà pọ́njú-pọ́njú
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-10B15. B15.
ICD/CIM-9070.0, 070.1 070.0, 070.1
DiseasesDB5757
MedlinePlus000278

Ó sábà maa ń ràn nípa jíjẹ tàbí mímu oúnjẹ tàbí omi ẹlẹ́gbin tí ó ní ìgbẹ́ àkóràn. Ẹja eléèpo tí a kò sè dáadaa jẹ́ orísun tí ó wọ́pọ̀. Ó tún lè ràn nípa ìfarakàn ẹni tí ó ní àkóràn. Bí àwọn ọmọdé ò ti ní àwọn ààmì àkóràn bẹ́ẹ̀ wọ́n ṣì le Koran ẹlòmíràn. Lẹ́hìn àkóràn àkọkọ́ ènìyàn kòle ní àkóràn mọ́ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀. Ìmọ̀ àisàn nílò àyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀ bíi àwọn ààmì rẹ̀ ṣe farajọ àwọn ti ààrùn míìrán. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn máàrún tí a mọ̀ ààrùn ẹ̀dọ̀ àwọn àkóràn: A, B, C, D, àti E.

òògùn ààrùn ẹ̀dọ̀ A dára fún ìdẹ́kun. Àwọn orílẹ̀ èdè kan fọwọ́si níwọ̀nba fún àwọn ọmọdé àti fún àwọn tí ó wà léwu gidi tí akòití fún ní oogùn rẹ. Ó hàn pé ó dára fún ẹ̀mí. Àwọn ìwọ̀n ìdẹ́kun míìrán ni ọwọ́ fífọ̀ àti síse oúnjẹ dáradára. Kòsí ìtọjú kan pàtó, pẹ̀lú ìsinmi àti àwọn oogùn fún ìṣu tàbí ṣíṣunú ni a fọwọsí bí o ti yẹ lóòrekoorè. Àwọn àkóràn sábà maa ńlọ pátápátá láìsi àrùn ẹ̀dọ̀ rárá. Ìtọjú fún àrùn ẹ̀dọ̀ líle, bí ó bá wáyé, ni pẹ̀lú Ìrọ́pò ẹ̀dọ̀.

Lágbayé láàrín 1.5 mílíónù àwọn ìṣẹlẹ̀ ààmì maa ń wáyé lọdọọdún èyí tí o ṣèéṣe àwọn àkóràn mílíónù ọ̀nà mẹ́wà ní gbogbo. Ó wọ́pọ̀ l’áwọn apa ẹkùn kan lágbayé tí wọn kìí tíṣe ìmọtótó dáradára àti tí kòsí omi tó. Ní àwọn orílẹ̀ èdè tí ó ṣẹ̀ẹ̀ṣẹ̀ ń gbèrú ìdá 90% àwọn ọmọdé ni o tiní àkóràn ní ọmọ ọdún 10 wọn kòsì le ni mọ́ ní àgbà. O máa ń ṣẹlẹ̀ níwọ̀nba ní àwọn orílẹ̀ èdè tí o ti gbèrú níbi tí àwọn ọmọdé kòní àkóràn ní kékeré tí kòsí sí ìwọ́pọ̀ ìfún lóògùn. Ní 2010, àrùn ẹ̀dọ̀ líle A fa ikú 102,000. Àyajọ́ ọdún ààrùn ẹ̀dọ̀ àgbayé ó maa ń wáyé lọ́dọọdún ní July 28 láti mú kí àwọn ènìyàn mọ́ọ̀ ààrùn ẹ̀dọ̀ líle.

Àwọn ìtọ́kasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

IkejaÀṣà Yorùbá.twIPhoneMichael CostelloÀwọn Filipínò29 JulyAbdul-Azeez Olajide AdediranElizabeth BlackburnAderonke ApataỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá).tkÀkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ ÈkóApple Inc.Thomas Adeoye LamboÌṣeọ̀rọ̀àwùjọEugenio MontaleOwe YorubaBahtMichael Bamidele OtikoAdo EkitiOrissa (India)Èdèe YorùbáVespasianIṣẹ́ Àgbẹ̀Kelechi IheanachoMikhail BakuninÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáGbFamily on FireNarendra ModiÈdè FaranséCristóbal MendozaGùyánà FránsìIfáDJ Cuppy29 OctoberHÀtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn Lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàLeptospirosisKady TraoréJacqueline WolperRadio Studio 54 Network2022AYorùbáMáàdámidófòPakístàn5 DecemberWerner HeisenbergÀsìá ilẹ̀ HàítìWikipẹ́díà l'édè YorùbáÀwọn ọmọ ÍgbòDJ XclusiveÈdè YorùbáOpen Amẹ́ríkà 2012 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanArabDonald J. CramLilian EsoroÌsọ̀kan Sófìẹ̀tìJohn TylerÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunAdeniran OgunsanyaAhmed Abdallah Mohamed SambiLinuxBukola SarakiMayotteLuther VandrossTunde NightingaleCarlos Mesa🡆 More