Luther Ronzoni Vandross tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù Kẹ́rin ọdún 1951, (April 20, 1951 – July 1, 2005) jẹ́ akọrin , olùgbé-orin jáde àti àkọsílẹ̀ ìgbàsílẹ̀ ará Amẹ́ríkà.
Nígbà ayé rẹ̀, Vandross ta àwon orin tó ju mílíọ́nù márùnlélógún lọ bẹ́ẹ̀ sì ni ó gba Ẹ̀bùn Grammy mẹ́jọ nínú wọn ní Best Male R&B Vocal Performance ni ẹ̀mẹrin. Ó gba ẹ̀bùn Grammy mẹ́rin ní ọdún 2004 nínú wọn ni Grammy Award for Song of the Year fún orin "Dance with My Father", tó kọ pẹ̀lú Richard Marx.
Luther Vandross | |
---|---|
Luther Vandross ní Madison Square Garden ti New York City ní October 5,1988. | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Luther Ronzoni Vandross |
Ọjọ́ìbí | New York, New York, United States | Oṣù Kẹrin 20, 1951
Aláìsí | July 1, 2005 Edison, New Jersey, United States | (ọmọ ọdún 54)
Irú orin | R&B, soul, adult contemporary, soft rock, soul jazz, quiet storm |
Occupation(s) | Singer-songwriter, Musician, record producer |
Instruments | Vocals, Keyboards |
Years active | 1968–2005 |
Labels | Cotillion, Epic, Virgin, J, Legacy |
Associated acts | Change, Chic, Dionne Warwick, Mariah Carey, Richard Marx, Whitney Houston |
Website | luthervandross.com |
Luther Vandross jẹ́ akọrin tó múná dóko nítorí náà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn akọrin bíi tirẹ̀ tó dángájíyá fẹ́ kí ó bá wón ṣe àwo orin pọ̀ , lára wọn ni Diana Ross , David Bowie , Donna Summer àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Luther Vandross ṣe aláìsí ní ọjọ́ July 1 2005 , látàrí àìsàn ọkàn.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Luther Vandross, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.