Johann Carl Friedrich Gauss (pípè /ˈɡaʊs/; listen (ìrànwọ́·ìkéde), Látìnì: Carolus Fridericus Gauss) (30 April 1777 – 23 February 1855) je ara Germany onimo-mathematiki ati onimosayensi ti o ko ipa to se koko ninu opo omo ijinle, bi iro nomba, statistiki, ituyewo mathematiki, Jeometria oniyato, geodesy, geophysics, electrostatics, itorawo ati iriran.
Won pe ni Princeps mathematicorum (Latini, fun "Arole awon Onimo-mathematiki" tabi "asiwaju awon onimo-mathematiki") ati "onimo-mathematiki olokikijulo lati atijo", Gauss ko ipa gidigidi ninu opo papa imo mathematiki ati sayensi. He referred to mathematics as "the queen of sciences."
Carl Friedrich Gauss | |
---|---|
Johann Carl Friedrich Gauss (1777–1855), painted by Christian Albrecht Jensen | |
Ìbí | Braunschweig, Electorate of Brunswick-Lüneburg, Holy Roman Empire | 30 Oṣù Kẹrin 1777
Aláìsí | 23 February 1855 Göttingen, Kingdom of Hanover | (ọmọ ọdún 77)
Ibùgbé | Kingdom of Hanover |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | German |
Pápá | Mathematician and physicist |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Göttingen |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Helmstedt |
Doctoral advisor | Johann Friedrich Pfaff |
Other academic advisors | Johann Christian Martin Bartels |
Doctoral students | Friedrich Bessel Christoph Gudermann Christian Ludwig Gerling Richard Dedekind Johann Encke Johann Listing Bernhard Riemann Christian Peters Moritz Cantor |
Other notable students | August Ferdinand Möbius Julius Weisbach L. C. Schnürlein |
Ó gbajúmọ̀ fún | See full list |
Influenced | Sophie Germain |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Copley Medal (1838) |
Signature |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Carl Friedrich Gauss, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.