Bẹ̀lárùs, (pípè /bɛləˈruːs/ ( listen) bel-ə-ROOS; Bẹ̀l.
Беларусь, Rọ́síà: Беларусь or Белоруссия, Belorussia see Etymology), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Bẹ̀lárùs, je orile-ede ayikanule ni Apailaorun Europa, to ni bode bi owo-ago pelu Rosia ni ariwailaorun, Ukrein ni guusu, Poland ni iwoorun, ati Lithuania ati Latvia si ariwaiwoorun. Oluilu re ni Minsk; awon ilu re pataki miran tun ni Brest, Grodno (Hrodna), Gomel (Homiel), Mogilev (Mahilyow) ati Vitebsk (Viciebsk). Idalogorun ogoji 207,600 square kilometres (80,200 sq mi) re lo je igbo aginju, be sini apa okowo re to tobijulo ni ise agbe ati ise elero.
Рэспубліка Беларусь Республика Беларусь Republic of Belarus | |
---|---|
Orin ìyìn: Дзяржаўны гімн Рэспублікі Беларусь (Belarusian) Dziaržaŭny himn Respubliki Biełaruś (transliteration) State Anthem of the Republic of Belarus | |
Ibùdó ilẹ̀ Bẹ̀lárùs (green) on the European continent (dark grey) — [Legend] | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Minsk |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Belarusian Russian |
Orúkọ aráàlú | Belarusian |
Ìjọba | Presidential republic |
• President | Alexander Lukashenko (Александр Лукашенко) |
• Prime Minister | Roman Golovchenko (Раман Галоўчанка) |
Independence from the Soviet Union | |
• Declared | 27 July 1990 |
• Established | 25 August 1991 |
• Completed | 25 December 1991 |
Ìtóbi | |
• Total | 207,600 km2 (80,200 sq mi) (85th) |
• Omi (%) | negligible (2.830 km2)1 |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 9,648,533 (86th) |
• 1999 census | 10,045,200 |
• Ìdìmọ́ra | 46.7/km2 (121.0/sq mi) (142nd) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $120.750 billion |
• Per capita | $12,737 |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $48.973 billion |
• Per capita | $5,165 |
Gini (2002) | 29.7 low |
HDI (2007) | ▲ 0.826 Error: Invalid HDI value · 68th |
Owóníná | Belarusian ruble (BYR) |
Ibi àkókò | UTC+2 (EET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+3 (EEST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 375 |
Internet TLD | .by |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Bẹ̀lárùs, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.