Ọjọ́ Ajé

Ọjọ́ ajé jẹ ọjọ́ tí ó wà láàrin ọjọ́ àìkú àti ọjọ́ ìṣẹ́gun.

Gégé bí àjọ International Organization for Standardization's ISO 8601 se sọ, ọjọ́ ajé ni ọjọ́ àkọ́kọ́ nínú ọ̀sẹ̀, àwọn orílẹ̀-èdè míràn tí ó ka ọjọ́ àìkú sí ọjọ́ àkókò inú ọ̀sẹ̀ sì ka ọjọ́ ajé sí ọjọ́ kejì inú ọ̀sẹ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè ni ó sọ ọjọ́ ajé ní orúkọ tẹ̀lé òṣùpá.

Ọjọ́ Ajé
àwòrán Galileo nípa òṣùpá ní ọdún 1616. Wọ́n sọ ọjọ́ ajé ní orúkọ tẹ̀lẹ́ òṣùpá ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè.

Ipò láàrin ọ̀sẹ̀

Ní ayé àtijó, ọ̀sẹ̀ àwọn Gíríìkì àti Róòmù bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ àìkú(dies solis), tí ọjọ́ ajé sì jẹ́ ọjọ́ kejì ọ̀sẹ̀(dies lunae). Bẹ́ẹ̀ tún ni, ní ariwa America, wón ka ọjọ́ àìkú sí ọjọ́ àkọ́kọ́ inú ọ̀sẹ̀. Ṣùgbọ́n

International Organization for Standardization fi ọjọ́ ajé sí ipò àkọ́kọ́ nínú ọ̀sẹ̀ ní ISO 8601. Àwọn ará China ma ń pe ọjọ́ ajé ní xīngqīyī (星期一) èyí tí ó túmọ̀ sí "ọjọ́ àkọ́kọ́ ọ̀sẹ̀".

Ìbọ̀wọ̀ àwọn ẹṣin fún ọjọ́ ajé

Ẹ̀sìn Kristẹni, islam àti Judaism ka ọjọ́ ajé sí ọjọ́ tí ó wà fún àwẹ̀. Àwọn Hadith kọ̀kan wípé ọjọ́ ajé jẹ́ ọjọ́ tí wón bí Muhammadu, ọjọ́ ajé ṣì ní ọjọ́ tí ó rí ìṣípayá rẹ̀ àkọ́kọ́, èyí tí ó padà di Quran.

Àwọn Ìtókasí

Tags:

ISO 8601International Organization for StandardizationỌjọ́Ọ̀sẹ̀

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Oṣù KejìA23 JuneÈdè YorùbáÀjẹsára Bacillus Calmette–GuérinOgun Àgbáyé KìíníRichard NixonInternet Relay ChatTeni (olórin)Yunifásítì HarvardPakístànKàlẹ́ndà GregoryMicrosoftISO 3166-1 alpha-2Owo siseÌtàn3GP àti 3G2WikisourceSeattleISBNOwe YorubaAyéIlẹ̀ YorùbáAjáMọ́remí ÁjàṣoroWiki CommonsAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéRọ́síàXAfghanístànJapanJẹ́mánìSaadatu Hassan LimanOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀwòrán kíkùnSean ConneryAbdulaziz UsmanÈdè Rọ́síàVladimir NabokovOlu FalaeẸ̀tọ́-àwòkọEast Caribbean dollarÈṣùMyanmarÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÁsíàLebanonApple Inc.Yul EdochieBahrainJakartaVictor Thompson (olórin)OlógbòẸ̀bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀MediaWikiUrszula RadwańskaBùrúndìGúúsù Georgia àti àwọn Erékùṣù Gúúsù SandwichWeb browserBeirut🡆 More