Ọkọ̀ ojú-omi Akérò jẹ́ àgbàyanu ọkọ̀ akérò, akẹ́rù, tí ó lé rin irin-àjò káàkiri àgbáyé lórí alagbalúgbú omi.
Ọkọ̀ ojú-omi akérò tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ohun ìrìnsẹ̀ tí ó ń ṣe ọmọnìyàn ní ànfàní pupọ̀, yálà fún iṣẹ́,okòwò tàbí ìṣèwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ọkọ̀ ojú-omi Akérò, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.