Ọkọ̀ tàbí Mọ́tò (ni ó wá láti inú èdè Látìnì: vehiculum) ni ó jẹ́ ẹ̀rọ tí ó ń gbé ènìyàn tàbí ẹrù láti ibìkan sí ibòmíràn.
Ọkọ̀ lè jẹ́ kẹ̀kẹ́ Alùpùpù, kẹ̀kẹ́, ọkọ̀ àjàgbé, Rélùwéè, ọkọ̀ ojú-omi, ọkọ̀ akérò, ọkọ̀ akérò ojú-omi, ọkọ̀ òfurufú , bàlúù ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ọkọ̀ arinlẹ̀ ni a pín sí Àwọn ọkọ̀ tí wọ́n ń lo ipá tí s mọ̀ sí (force) láti fi lè kúrò ní ojú kan sí òmíràn Webstore.anis.org
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Mọ́tò, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.