Ìdìbòyàn

Ìdìbò jẹ́ ìpinnu àti ìgbésẹ tí àwọn ènìyàn kan gbà láti yan ẹni tí yóò ṣojú tàbí darí wọn sípò.

Ìdìbòyàn
Ọwọ́ tó ń dìbò.

Ìdìbò ti jẹ́ èròjà ìṣèjọba àwaarawa láti bíi sẹ́ńtúrì mẹ́tàdínlógún sẹ́yìn. A máà ń lò ó fún yíyan ni sípò aṣòfin àti ti aṣojúṣòfin àti sí Ìjọba ìbílẹ̀ pẹlú ti ẹlẹ́kùnjẹkùn. Ìgbésẹ yìí tún wọpọ ní àwọn Ilé-iṣẹ́ ńlá-ńlá àti ti aládani pẹlú àwọn ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́.

Ìlo káríayé ìdìbò gégé bí èròjà fún yíyan asojú tí ó wọpọ ní ìjọba àwaarawa ti àsìkò yìí wà ní ìyàtọ̀ sí ti ayé àtijọ́ nigbati yíyan ni sípò máa ń wáyé nípa lílosortition,Ẹni orí yàn tabi kádàrá nípa ṣíṣe èyí-jẹ-èyí-o-jẹ láti fi yàn wọ́n sípò.

Àtúnṣe sí ètò ìdìbò ṣe àfihàn àwọn ìgbésẹ tí wọ́n ń se fun ìrọwọ́-ìrọsẹ̀ nínú ètò ìdìbò tàbí síṣe àtúnṣe sí àwọn ètò ìdìbò tí ó wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀. PsephologySífọ́lọ́jì jẹ́ ẹ̀kọ́ nípa èsì ìdìbò àti àwọn ìṣirò mìíràn tí ó rọ̀mọ́ ètò ìdìbò ní pàtàkì jùlọ láti ṣírò èsì ìdìbò náà síwájú kíkéde rẹ̀. Ìdìbò jẹ kókó dídìbòyàn tàbí ìdìbòyan

Láti "dìbò" túmọ sí láti Yàn tàbí ṣe "ìpinnu" àti nígbà mìíràn,wọn máa ń lo àwọn ìwé pélébé aláfọwọ́jù sínú àpótí gégébí ìdìbò(referendum).Ìlú Amẹ́ríkà ní èyí tí wọ́pọ̀ jùlọ.

Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Èdè FaranséWerner ArberISO 4217Atlántico DepartmentFriedrich NietzscheInternet Movie DatabaseYang di-Pertuan AgongLúksẹ́mbọ̀rgÌgbà DẹfoníàÌrẹsìÀkàyéAnneri EbersohnFyodor DostoyevskyKManuel A. OdríaẸ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì GbàngbàMicrosoftAlfred DeakinÌnáwóIndo-European languagesSan FranciscoASCIIÌmúrìnPAndrew FisherÁktínídìJurelang ZedkaiaUÍndíàEBÀtòjọ àwọn akọ̀ròyìn ilẹ̀ NàìjíríàBola TinubuBeninÒkunPaul-Henri MathieuInstagramJamaikaTallinnÈbuTsẹ́kì OlómìniraLahoreQIllinoisObìnrinRosa ParksBrooklynÈdè SpéìnFilnius19 OctoberAstatineÀàlàAdo-EkitiGerman languageJuan Antonio RíosÌbálòpọ̀ÌlúỌjọ́rúAmmanManila9 February.liJohn McEwenArméníàÒrò àyálò YorùbáOṣù KàrúnSheik Muyideen Àjàní BelloFránsì🡆 More