Wolfgang Amadeus Mozart

Wọ́n bí Mozart ní 1756.

Ó kú ní 1791. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú tí ó máa ń ‘Compose’ orin. Gbajúgbajà ni nínú iṣẹ́ yìí. Láti nǹkan bí ọmọ ọdún mẹ́ta ni ó ti ní etí inú fún orin. Láìpé sí ìgbà yìí ni ó ti bẹ̀rẹ̀ sí níí lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ irin iṣẹ́ tí wọ́n fi ń kọrin. Salzburg ní Austria ni wọ́n ti bíi. Ìlú yìí ni bàbá rẹ̀ ti ń ṣiṣẹ́ orin kíkọ ní ààfin Archbishop ti Salzburg.

Wolfgang Amadeus Mozart
Wolfgang Amadeus Mozart

Ọmọ ọdún mẹ́fà ni Mozart nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin gan-an. Ó bá bàbá rẹ̀ àti à̀ǹtí rẹ̀ ṣe ìrìnàjò lọ sí ìlú Òyìnbó. Àǹtí rẹ̀ yìí náà mọ orin-ín kọ gan-an ni. Gbogbo ènìyàn ló ń gbé wọn gẹ̀gẹ́ ní gbogbo ibi ti wọ́n lọ. Ìgbà yìí ni Mozart ti bẹ̀rẹ̀ síí kọ orin fún ara rẹ̀.

Kò sí irú orin tí Mozart kò lè kọ. Ó ń kọ opera, choral music, orchestral music àti chamber music. Ara àwọn opera tí ó kọ ni ‘The Marrcege of figaro’ ‘Dio Giovanni’ àti The Magic Flute’. Nínú wọn, the Magic Flute ni ó gbajúmọ̀ jù.

Lára àwọn symphonies bí ogójì tí ó kọ ‘Jupiter’ tàbí ‘Symphony C major’. ‘Symphony ni G minor’ àti ‘the Symphony in E flat major’ ni ọ̀pọ̀ sọ pé ó dára jù lára iṣẹ́ rẹ̀. Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ mìíràn tí ó lápẹrẹ ni ‘Eine Kleine Nachtmusik’ ti ó jẹ́ ‘serenade’ àti ‘Sinfonia Concertante’ tí ó jẹ́ ‘concerto’ fún violin àti viola.

Lékèé gbogbo iṣẹ́ tí ó ṣe yìí, kò lówó. Ọmọ ọdún márùndínlógájì péré ni nígbà tí ó kú wọ́n sì sin ín sí ibi tí wọ́n máa ń sin àwọn òtòsì sí ní Vienna.


Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

OmanPierre NkurunzizaPaul KehindeLizardo Montero FloresPópù Benedict 16kSvalbardJuho Kusti Paasikivi9007 James BondEre idarayaMaryam YahayaWindhoekTuedon MorganElisabeti KejìXAma Ata Aidoo.qaÍsráẹ́lìAdrienne KoutouanOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́TripoliAmalia PerezÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáLatefa AhrarX3DGrace EborLÈdè KàsákhìHerbert MacaulayÀwọn ará Jẹ́mánìBerom languageJanusz WojciechowskiSaint HelenaTim RobbinsÀtòjọ àwọn ilé-ìtura ní NigeriaOtto von BismarckUgandaThuliumỌrọ orúkọFrançois HollandeKàmbódíàÁpártáìdìNamibiaÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Microsoft WindowsJane AsindeISO 14644-8Àtòjọ Àwọn Olú-ìlú Àwọn Orílẹ̀-èdè Ní ÀgbáyéPrince (olórin)Alice BradyLars OnsagerDòmíníkàAbu DhabiẸ́gíptìAdájọ́Daisy DucatiMàkáùhucnhMitsumasa Yonai🡆 More