Winston Churchill

Winston Leonard Spencer-Churchill, KG, OM, CH, TD, PC, FRS (30 November 1874 – 24 January 1965) je oloselu ara Britani ti o gbajumo fun isolori re fun orílẹ̀-èdè Isodokan Ile-Oba ni asiko Ogun Agbaye Keji.

O di Alakoso Agba Britani lati 1940 de 1945 ati lekansi lati 1951 deo 1955. Asiwaju pataki ati adoroso, Churchill tun je ogagun ni ise Adogun Britani, onitankiko, olukowe ati asona. Doni, ohun nikan ni he Alakoso Agba Britani to ba Ebun Nobel ninu Litireso, ati eni keji ti o je niyi bi Araalu Oniyi Isodokan awon Ipinle Amerika.

The Right Honourable

Sir Winston Churchill


KG OM CH TD FRS PC
Winston Churchill
Prime Minister of the United Kingdom
In office
26 October 1951 – 7 April 1955
MonarchGeorge VI
Elizabeth II
DeputyAnthony Eden
AsíwájúClement Attlee
Arọ́pòAnthony Eden
In office
10 May 1940 – 27 July 1945
MonarchGeorge VI
DeputyClement Attlee
AsíwájúNeville Chamberlain
Arọ́pòClement Attlee
Chancellor of the Exchequer
In office
6 November 1924 – 4 June 1929
Alákóso ÀgbàStanley Baldwin
AsíwájúPhilip Snowden
Arọ́pòPhilip Snowden
Home Secretary
In office
19 February 1910 – 24 October 1911
Alákóso ÀgbàHerbert Henry Asquith
AsíwájúHerbert Gladstone
Arọ́pòReginald McKenna
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kọkànlá 1874(1874-11-30)
Blenheim, Oxfordshire, England
Aláìsí24 Oṣù Kínní 1965 (ọmọ ọdún 90)
Hyde Park, London, England
Resting placeSt Martin's Church, Bladon, Oxfordshire, England
Ọmọorílẹ̀-èdèBritish
Ẹgbẹ́ olóṣèlúConservative
(1900–1904, 1924–1964)
Liberal (1904–1924)
(Àwọn) olólùfẹ́Clementine Churchill
ẸbíPamela Harriman, daughter-in-law
Àwọn ọmọDiana Churchill
Randolph Churchill
Sarah Tuchet-Jesson
Marigold Churchill
Mary Soames
Residence10 Downing Street (official)
Chartwell (private)
Alma materHarrow School, Royal Military Academy Sandhurst
ProfessionMember of Parliament, statesman, soldier, journalist, historian, author, painter

Nigba to wa nibise ajagun, Churchill kopa ninu ise ologun ni India, Sudan ati Ogun Boer Keji. O gbajumo gege bi afiroyinranse ogun ati awon iwe to ko lati sejuwe awon ohun ton sele. Bakanna o tun sise ni ibise Adogun Britani ni Ojuogun Apaiwoorun ninu Ogun Agbaye Akoko, nibi to tidari awon Eso 6th ti Royal Scots Fusiliers.


Itokasi

Tags:

BritaniNobel Prize in LiteratureUnited KingdomWorld War II

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Mariam Alhassan AloloÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáAnkaraÌtòràwọ̀MicrosoftÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020Yemoja11 AprilOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà5 DecemberHorsepowerFirginia.cd7082 La SerenaÒṣèlú6 AugustFrancisco FrancoSantos AcostaDenrele Edun27 NovemberỌ̀yọ́túnjíÌwọ́ ìtannáMercedes-BenzÀwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyànÈdè IjọEmmanuel AmunikeOlusegun Olutoyin AgangaOṣù KejìTòmátòWikiÍslándìÀkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnóÀlọ́24 AprilPierre NkurunzizaAung San Suu KyiWerner Faymann.geSheik Muyideen Àjàní BelloGoogleÀsìá ilẹ̀ KánádàEminemGuinea-BissauLos AngelesPópù Adrian 4kEconomicsMalek JaziriMasẹdóníà ÀríwáIlerioluwa Oladimeji Aloba (Mohbad)Yunifásítì HarvardRepublican Party (United States)Ọ́ksíjìnGúúsù Amẹ́ríkàLionel BarrymoreVictor AnichebeBerenice IV of EgyptISO 639-3RáràXÌbálòpọ̀Web browserẸkún ÌyàwóCarlos SoubletteAdolf HitlerPópù Jòhánù 14kGregor Mendel🡆 More