Irinṣẹ́ Ìdápadà ẹ̀tọ́ oníṣẹ́ ni ó ma fún oníṣẹ́ tí ó ní àṣẹ àsíá ní bọ́tìnì (ìdápadà), tí yóò lè ṣe ìdápadà àṣìṣe tàbí ìbàjẹ́ tí ó ti ọwọ́ oníṣẹ́ kan wá ní tẹ̀lé-n-tẹ̀lé ní ọwọ́ kan.
Irinṣẹ́ yí wúlò láti ṣàyípadà ìbàjẹ́ ojú-ewé.
Oníṣẹ́ tí ó ní àṣẹ ìdápadà yóò ní bọ́tìnì tí ó ní àwọn irinṣẹ́ mìíràn lójú ìwò oníṣẹ́, lórí ojú-ewé oníṣẹ́ oníṣẹ́ náà àti àti (tiwọn), àti ti ojú-ewéìtàn.
Irinṣẹ́ ìdápadà ni ó wà fún alákòóso àgbà láì sí ìdíwọ́, a sì tún lè fún oníṣẹ́ tí ó bá bèrè fun lábẹ́ ìyọnda alákòóso agbà. Ẹnkẹ́ni tí ó bá ní àsíá yí ni a ń pè ní aláyìípadà. Lọ́wọ́ yí, iye àwọn oníṣẹ́ tí ní àṣẹ yí ni olóòtú àgbà àti4 administrators and 0 (6 total), ó yàtọ̀ sí aláyìípadà gbogbo gbò alákòóso gbogbo gbò tí ó ti ní àṣẹ àti agbára láti ṣe ohun kóhun lórí àwọn pèpéle Wiki pátá.
Àwọn àsìkò tí a lè lo irinṣẹ́ ìdápadà oníṣẹ́ tí ó bá ṣi irinṣẹ́ yí lò nípa yí yí àpilẹ̀kọ gidi dà sí àìda (bí àpẹrẹ) tí ó sì hàn lábẹ́ iṣẹ́ wọn yóò pàdánù àṣẹ àti àsíá irinṣẹ́ ìdápadà rẹ̀, fẹ̀kàn tẹ́lẹ̀, olóòtú tàbí alákòóso àgbà nìkan ló ní ẹ̀tọ́ sí irinṣẹ́ náà jùlọ. Olóòtú àgbà lè bèrè kí wọ́n yọ òun nípò kí ó lè pàdánù àṣẹ ìlò irinṣẹ́ náà.
Olóòtú àgbà lè fòpin sí àṣẹ ìdápadà tàbí kí ó fagilé oníṣẹ́ tí wọ́n fún ní àṣẹ ilò irinṣẹ́ ìdápadà nígbà tí kò bá lè ṣe alàyé lórí ìdápadà tí ó bá ṣe lórí bí ó ti wulẹ̀ kí ó rí. Ẹ̀wẹ̀, a ní láti fàyè gba oníṣẹ́ tí wọ́n fún ní àṣẹ ilò irinṣẹ́ ìdápadà láti ṣàlàyé kí ó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ ìdí tí ó fi ṣe àyípadà rẹ̀.
Láti béèrè fún àṣẹ yí, tọrọ rẹ̀ request rollback rights, ask at Wiki: Requests for permissions/níbí tàbí kí o béèrè lọ́wọ́ àwọn olóòtú àgbà níbí. Èyíkéyí Any olóòtú àgbà ni ó lè yọ̀nda tàbí gba àṣẹ náà kúrò lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá fún. Ẹ wo ojú-ìwé àwọn ẹ̀tọ́ oníṣẹ́.
Lóòtọ́, kò sí ohun àmúyẹ kánkán tí a ma ń wò kí a tó fún ẹnkẹ́ni tó bèrè fún àṣẹ ìlò irinṣẹ́ ìdápadà ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá fẹ́ lo àṣẹ yí ní láti ṣiṣẹ́ jìnà tí àwọn iṣẹ́ rẹ̀ yóò sì ma tọ́ka sí akitiyan rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ní àgbọ́nọ̀gbẹ ìmọ̀ àti ìrírí nípa dídá àti ìlè ṣe ìyàtọ̀ láàrín àṣìṣe àti ìbàjẹ́ tí oníṣẹ́ kan bá ṣe sí ijú-ìwé àyọkà tàbí àpilẹ̀kọ kan. Irinṣẹ́ ìdápadà (rollback) kò sí fún àwọn oníṣẹ́ titun. Láfikún, oníṣẹ́ tí ó bá ma ń fa whálà pẹ́lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ lọ́pọ̀ ìgbà kó ní lẹ́tọ̀ọ́ sí irinṣẹ́ abiyi yí; nítorí kí má ba máa sìílò lọ́nà ìjàmbá.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Wiki:Rollback, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.