ìtọ́nisọ́nà

Ojú ewé yìí ní kúkukú: Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà jẹ́ Ojú ewé tó tọ́ka sí ìlànà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ Wikipédíà.

ìtọ́nisọ́nà Ojúewé yìí ní ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kan Wikipedia nínú. Ó jẹ́ èso ìfohùnṣọ̀kan, bẹ́ ẹ̀ sì ni ó jẹ́ gbígbàgbọ́ pé gbogbo àwọn oníṣe gbọ́dọ̀ tẹ̀lé wọn gbámúgbámú. Ẹ le ṣàtúnṣe àkóónú ojúewé náà sùgbọ́n ẹ jọ̀wọ́ ọ mọ́ ṣe ìyípadà ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kankan láì kọ́kọ́ filọ àwọn oníṣe yìókù.
Àkékúrús:
WP:Ìmúlò
WP:Ìtọ́nisọ́nà
WP:ÌÌ

Ìmúlò yìí ṣe àpèjúwe bí a ṣe lè máa mú ìdàgbàsókè bá àwọn Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà.

Àwùjọ Wikipédíà ṣe Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà yìí lati ṣe àpèjúwe ọ̀nàn tó dára jùlọ lati ṣàgbékalẹ́ ọ̀rọ̀, yanjú ìjà àti lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìlépa wa fún ṣiṣẹda ìmọ ọfẹ. Kò pọn dandan lati ka Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ojú ewé yìí lati bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ṣíṣàtúnkọ. Wikipédíà:Orígun máàrún Wikipédíà ṣe àlàyé ránpẹ́ nípa ìlànà Wikipédíà. Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé Wikipédíà Kò ní gba lílé ati sáré òfin, àwọn ojú ewé Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ti ṣàgbékalẹ́ bí ohun gbogbo ṣe gbọ́dọ̀ máa lọ. Ìmúlò ṣe àlàyé àwọn ìlànà tí alàtúnkọ gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ Wikipédíà. Bakan náà ni ìtọ́nisọ́nà ṣe àlàyé ọ̀nàn tí a yàn lááyò lati tẹ̀lé ìlànà yìí. A gbọ́dọ̀ máa lo ìtọ́nisọ́nà pẹ̀lú láákáyè.

Ìpinlẹ̀ṣẹ̀

Àjọ kòsí fún èrè Wiki Foundation ni ó n se alàkóso Wikipédíà pẹ̀lú àwọn òfin kan (wo ibí fún àkójọ Ìmúlò). Tún wo Ipa Jimmy Wales. ṣùgbọn, Wikipédíà ṣàkóso ara ẹ̀ nipase oníwé àwùjọ

Ipa

Àkékúrú:
WP:Ìmúlò

Ìmúlò jẹ́ ohun tí gbogbo alàtúnkọ gbà. Osì tún se àpèjúwe ìlànà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ. Gbogbo ojú ewé ìmúlò wà ní Wikipédíà: Gbogbo ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà àti. Fún kúkurú ojúlówó àwọn ìmúlò, wo Wikipédíà: Àwọn ìmúlò

Wiki Yorùbá únlo àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ tó wà fún Wikipedia èdè Gẹ̀ẹ́sì.

Tí ẹ bá fẹ́ ẹ lè lọ sí ojúewé ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti fọ̀rọ̀wérọ̀ nípa wọn tàbí dámọ̀ràn ìpínu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ míràn

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ṣakí.egFrançois FillonÀdírẹ́ẹ̀sì IPAminu Ado BayeroJ. K. AmalouOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́.kySérbíà àti MontenégròOkpokoJuliu KésárìAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-OsiBobriskyXBeninLev BùlgáríàLa RéunionISO 19011José Miguel de Velasco Franco17 MarchẸgbẹ́ kọ́múnístìÌtòràwọ̀Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ifelodun, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣunOwe YorubaKúbàTurkeyBill ClintonÌpínlẹ̀ GeorgiaMediaWikiFránsìAlfonso García RoblesTibetAdrien BrodyNọ́mbà tíkòsíUnited Nations.aqMọ́remí ÁjàṣoroSaadatu Hassan LimanDonald TuskÒrùnÁntíllès àwọn Nẹ́dálándì2024POSIXMársìAdolf HitlerISO 10206Banky WMercedes-BenzÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáIvor Agyeman-DuahHilary SwankISO 639-3ZỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀.afPhoenix10 OctoberRonald ReaganÀgùtànAta ṣọ̀mbọ̀Mọ́skòGuinea-Bissau🡆 More