Weruche Opia

Reanne Weruche Opia (tí a bí ní 11 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 1987 ní Nàìjíríà) jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Bìrìtìkó, ó sì tún jẹ́ olùṣòwò.

Ó jẹ́ aláàkóso ilé ìtajà rẹ̀ tí ó dá sílẹ̀ táa pe orúkọ rẹ̀ ni Jesus Junkie Clothing.

Weruche Opia
Òṣèré àti oníṣòwò Weruche Opia ní ọdún 2017.
Weruche Opia
Ọjọ́ìbíReanne Weruche Opia
11 Oṣù Kẹẹ̀rin, Ọdún 1987
Nàìjíríà
Iṣẹ́òṣèré orí-ìtàgé

Ìṣẹ̀mí rẹ̀

Weruche gbajúmọ̀ fún kíkó ipa Cleopatra Ofoedo nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Bad Education. Ní Ọdún 2015, wọ́n yan Weruche fún àmì ẹ̀yẹ "Nollywood Actress of the Year" níbi ayẹyẹ 2015 Nigeria Entertainment Awards. Ní ọdún 2018, Opia dì jọ kópa pẹ̀lú Steve Pemberton àti Reece Shearsmith nínu ìpele ẹ̀kẹfà àti ìkẹhìn ti eré "Tempting Fate." Opia tún ti kópa nínu eré BBC kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ I May Destroy You, èyítí ó kọ́kọ́ jẹ́ gbígbé sáfẹ́fẹ́ ní Oṣù Kẹẹ̀fà Ọdún 2020. Opia ti ní oyè-ẹ̀kọ́ nínu eré ìtàgé àti ìmọ̀ àwùjọ. Ó jẹ́ ọmọ ògbólògbó agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti olùgbàlejò lóri ètò tẹlifíṣọ̀nù Ruth Benamaisia Opia.

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

Fíìmù
Ọdún Fíìmù Ipa Àwọn àkọsílẹ̀
2010 The Bill as Selina Moris TV series
2013 Top Boy as Nafisa
2014 Bad Education as Cleopatra starred in Series 3
When Love Happens as Mo
2015 Banana (TV series) as Lilia featured in 1 episode
The Bad Education Movie as Cleopatra Ofoedo
Hot Pepper as Toya featured in 1 episode
Suspects as Mae Roberts featured in 2 episodes
Prey (IV) as Ebele short film
2016 When Love Happens Again as Mo film sequel
Thereafter as June short film
2017 Just a Couple as Melissa TV series
2018 Inside No. 9 as Maz featured in 1 episode "Tempting Fate"
2019 Sliced as Naomi TV series featured in all 3 episodes
2020 I May Destroy You as Terry TV Series

Àwọn ìyẹ́sí rẹ̀

Ọdún Ayẹyẹ Àmì-ẹ̀yẹ Èsì ìtọ́kasí
2015 2015 Nigeria Entertainment Awards Actress of The Year (Nollywood) Wọ́n pèé
3rd Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actress in a Comedy Wọ́n pèé


Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Weruche Opia Ìṣẹ̀mí rẹ̀Weruche Opia Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀Weruche Opia Àwọn ìyẹ́sí rẹ̀Weruche Opia Àwọn ìtọ́kasíWeruche OpiaNàìjíríà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ClevelandJẹ́ọ́gráfì ilẹ̀ LíbyàPólándìMahmoud AhmadinejadEyvind JohnsonAtlántico DepartmentCERNÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020ṢìkágòÈkóÀkójọ àmì-ìdámọ̀ àwon apilẹ̀sẹ̀Steven SpielbergKíndìnrínBẹ́rkẹ́líọ̀mÀkàyé28 AprilẸlẹ́ẹ̀mín22 SeptemberÌsọdipúpọ̀YukréìnIfe-ẹ̀yẹ Àgbáyé Bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀TallinnSarajevoTẹ́nìsAustríà27 OctoberKrómíọ̀mùGordian 3kKikan Jesu mo igi agbelebuThe New York TimesUnited Nations Human Settlements ProgrammeCherAsoSali BerishaObìnrinDMarie-Joseph Motier, Marquis de LafayetteWikiDale T. MortensenÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáRamón CastillaNewfoundland àti LabradorIllinoisÀsìá ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàOgun Àgbáyé Kìíní.tzWerner ArberFederalismAymaraPierre MauroyGuamAisha YesufuÈdè SpéìnÒkunBrooklynÈdè SlofákíàJohannes HeestersThe BeatlesÓscar R. BenavidesAyn RandÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáBẹ́ljíọ̀mJÁntígúà àti Bàrbúdà29 FebruaryChadPepinOṣù Kínní 2Èdè Ìṣèlànà Kọ̀mpútàKinmenÈdè SwàhílìÌlàoòrùn ÁsíàJudi Dench🡆 More