Tóyìn Abraham: Oṣere fiimu ti orilẹ-ede Naijiria

Toyin Abraham tàbí Olutoyin Aimakhu; ni wọ́n bí ní (September 5, 1984).

Ó jẹ́ òṣèré orí ìtàgé , olùgbéré-jáde àti adarí eré, ọmọ rílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Toyin Abraham
Tóyìn Abraham: Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀, Iṣẹ́ rẹ̀, Àwọn eré ìtàgé rẹ̀
Toyin Abraham at AMVCA 2020
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kẹ̀sán 1980 (1980-09-05) (ọmọ ọdún 43)
Auchi, Edo, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • actress
  • filmmaker
  • producer
  • director
Ìgbà iṣẹ́2003–present
Olólùfẹ́Kolawole Ajeyemi

Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

Wọ́n bi ní ìlú Auchi, tí ó jẹẹ́ ìlú kan ní town in ìpínlẹ̀ Ẹdó ní orílẹ̀-èdẹ Nàìjírìà. Àmọ́ ṣá, ó bẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, tí ó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó gba ìwé ẹ̀rí HND (Higher National Diploma) ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ìlú Ìbàdàn ìyẹn (Ibadan Polytechnic), lásìkọ́ yí, ó jẹ́ akẹgbẹ́ pẹ̀lú Dibie, C.B.N aka x7, Tóyìn Abraham ti fara hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, tí ó sì tún ṣẹ̀ṣẹ̀ kópa nínú sinimá àgbéléwò aré tí orúkọ̀ rẹ̀ ń jẹ́ Black Val.

Iṣẹ́ rẹ̀

Tóyìn bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàgé rẹ̀ nígbà tí gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bukky Wright, wá sí ìlú Ìbàdàn láti yàwòrán eré kan .Ó ti darí, kópa àti gbé eré jáde fúnra rẹ̀, lára rẹ̀ ni Àlání Bàba Làbákẹ́ àti d Èmi ni. Wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ obìnrin tó dára jùlọ (Best Supporting Actress) nínú eré orí ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Ẹ̀bi mi ni" nínú àmì ẹ̀yẹ 2013 Best of Nollywood Awards , bákan náà ni wọ́n yan Jọkẹ́ Múyìwá fún Best Lead Actress nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ayítakẹ̀. Ẹ̀wẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn olóṣèlú ló ti pèé láti bá wọn polongo ètò ìdìbò fún Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí ó jẹ́ adíje dupò sí orí àpèrè Ààrẹ ìyẹn Goodluck Ebele Jonathan ní ọdún 2015. Tóyìn pàá pàà só wípé òun lè kú torí ẹgbẹ́ òṣèlú People Democratic Party (PDP) kú tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí adíje dupò náà ti ń díje. Àmọ́ ṣá, ó padà yí gbólóhùn rẹ̀ padà wípé òun bẹ àwọn olólùfẹ́ òun wípé kí ẹnikẹ́ni ó má ṣe ta ẹ̀jẹ̀ ẹnikẹni sílẹ̀ lásìkò ìdìbò.

Àwọn eré ìtàgé rẹ̀

  • Okafor's Law (2016)
  • Love is in the Hair (2016)
  • Àlàní Bàbá Làbákẹ́ (2013)
  • Ẹ̀bi mi ni (2013)
  • Alákadá (2013)
  • Ṣọlá fẹ́ pa mí
  • Ghost and the tout (2018)

Àwọn Fíìmù Rẹ̀ Tí A Yàn

Alani Baba labake (2013)

Ebi mi ni (2013)

Alakada (2013)

Okafor's Law (2016)

What Makes you Tick (2016)

Love is in the Hair (2016)

Alakada Reloaded (2017)

Esohe (2018)

Hakkunde (2017)

Mentally (2017)

Tatu (2017)

London Fever (2017)

Wives on Strike: The Revolution (2017)

Celebrity Marriage (2017) pẹ̀lú Tonto Dikeh, Felix Ugo Omokhodion , àti Jackie Appiah

The Ghost and the Tout (2018)

Seven and Half Dates (2018)

Disguise (2018)

What just happened (2018)

Elevator Baby (2019)

Don't Get Mad, Get Even (2019)

Made in Heaven (2019)

Two Weeks in Lagos (2019)

The Millions (2019)

Kasanova (2019)

Bling Lagosians (2019)

Nimbe (2019)

Diamonds In The Sky (2019)

Fate of Alakada (2020)

Dear Affy (2020)

Small Chops (2020)

Sola Fe Pami

Shadow Parties (2020)

Kambili (2020)

Fate of Alakada (2020)

Aki and Pawpaw

The Prophetess (2021)

The Therapist (2021)

Day of Destiny (2022)

King of Thieves (2022)

The stranger I know (2022)

The wildflower (2022)

Ẹ tún le wo

  • List of Nigerian film producers

Àwọn ìtọ́ka sí

Àwọn ìjásóde

  • Toyin Abraham on IMDb

Tags:

Tóyìn Abraham Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀Tóyìn Abraham Iṣẹ́ rẹ̀Tóyìn Abraham Àwọn eré ìtàgé rẹ̀Tóyìn Abraham Àwọn Fíìmù Rẹ̀ Tí A YànTóyìn Abraham Ẹ tún le woTóyìn Abraham Àwọn ìtọ́ka síTóyìn Abraham Àwọn ìjásódeTóyìn Abraham

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

KòlómbìàDolby DigitalISO 3166-1Ohun ìgboro27 JunePornhubFrançois FillonRenée ZellwegerAdeniran OgunsanyaFáwẹ̀lì YorùbáISO 4217Wiki23 OctoberOgunKòréà ÀríwáMarc FleurbaeyÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàOpen Amẹ́ríkà 1985 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanApáìlàoòrùn EuropeRwandaBlu-ray DiscCarlos SoubletteÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáQueen's CounselLẹ́tà Àìgbẹ̀fẹ̀VÌpínlẹ̀ ÒndóAkanlo-edeAlfonso García Robles7 AprilAdolf HitlerIlẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnDavid JemibewonISO 1901125 JulyKúbàFrancisco FrancoNse Ikpe-EtimISBNBobriskyOrúkọ YorùbáTẹlifísànWaterFestus KeyamoKenneth ArrowDÒrìṣà EgúngúnÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020Ivor Agyeman-DuahIlú-ọba Ọ̀yọ́3254 Bus.soSeye KehindeNancy Charton.bzParisiSunita WilliamsLebanonFirginiaCharlize TheronHorsepower23 AprilIkúÁljẹ́brà onígbọrọ🡆 More