Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ Ìpínlẹ̀ tí ó wà ní àárín gbùngbùn apá Ìwọ̀-Oòrùn Gúúsù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní Ìlú Òṣogbo. Ó ní ibodè ní àríwá mọ́ Ipinle Kwara, ní ìlà-oòrùn díẹ̀ mọ́ Ipinle Ekiti àti díẹ̀ mọ́ Ipinle Ondo, ní gúúsù mọ́ Ipinle Ogun àti ní ìwọ̀oòrùn mọ́ Ipinle Oyo. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ni Gómìnà Gboyega Oyetola . Wọ́n dìbò yàn-án wọlé ní 2018. Ọsun ní ibi tí ọ̀pọ̀ àwọn ibi mèremère tó gbajúmọ̀ wà. Ọgbà Yunifasiti Obafemi Awolowo to wa ni Ile-Ifẹ, ibi tó ṣe pàtàkì nínú àṣà Yorùbá. Àwọn ìlú tóṣe pàtàkì ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun tún ni Oke-Ila Orangun, Ila Orangun, Ede, Iwo, Ejigbo, Esa-Oke, Ìrágbìjí, Ada, Ikirun, Oke-Ila Orangun, Ipetu-Ijesha, Ijebu-Jesa, Erin Oke, Ipetumodu, Ibokun, Ode-Omu, Otan Ayegbaju, Ifetedo, Ilesa, Okuku, àti Otan-Ile. A da ipinle osun sile ni 27/08/1991.

Ọsun State
Osun State
Flag of Osun State
Flag of Osun State
Flag of Ọsun State
Flag
Nickname(s): 
Location of Ọsun State in Nigeria
Location of Ọsun State in Nigeria
CountryÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Itan, Ilé ẹ̀kọ́ gíga, Ijọba Ìbílẹ̀ Nigeria
Date created27 August 1991
CapitalOsogbo
Government
 • GovernorGboyega Oyetola (APC)
 • Deputy GovernorBenedict Gboyega Alabi
 • LegislatureOsun State House of Assembly
Area
 • Total9,251 km2 (3,572 sq mi)
Area rank28th of 36
Population
 (1991 census)
 • Total2,203,016
 • Estimate 
(2005)
4,137,627
 • Rank17th of 36
 • Density240/km2 (620/sq mi)
GDP (PPP)
 • Year2007
 • Total$7.28 billion
 • Per capita$2,076
Time zoneUTC+01 (WAT)
ISO 3166 codeNG-OS
Websitehttps://www.osunstate.gov.ng

Gboyega Oyetola ni gomina ipinle osun

Itan

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Itan, Ilé ẹ̀kọ́ gíga, Ijọba Ìbílẹ̀ 
Osun river in Osogbo, Osun state

Ibi tí a ń pè ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lo nii ni wọ́n da sileẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1999. Wọ́ ṣe àfàyọ ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun láti ara Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ wọ́n fún Ìpínlẹ̀ náà ní orúkọ rẹ̀ látara omi Odò Ọ̀ṣun ìyẹn omi tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá.

Ilé ẹ̀kọ́ gíga

Ijọba Ìbílẹ̀

Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Osun jẹ́ ọgbọ̀n. Awọn ná ní:

Ijọba Ìbílẹ̀ Olú ilé
Aiyedaade Gbongan
Aiyedire Ile Ogbo
Atakunmosa East Iperindo
Atakunmosa West Osu
Boluwaduro Otan Ayegbaju
Boripe Iragbiji
Ede North Oja Timi
Ede South Ede
Egbedore Awo
Ejigbo Ejigbo
Ife Central Ile-Ife
Ife East Oke-Ogbo
Ife North Ipetumodu
Ife South Ifetedo
Ifedayo Oke-Ila Orangun
Ifelodun Ikirun
Ila Ila Orangun
Ilesa East Ilesa
Ilesa West Ereja Square
Irepodun Ilobu
Irewole Ikire
Isokan Apomu
Iwo Iwo
Obokun Ibokun
Odo Otin Okuku
Ola Oluwa Bode Osi
Olorunda Igbonna, Osogbo
Oriade Ijebu-Jesa
Orolu Ifon Osun
Osogbo Osogbo

Àwọn èèyàn jànkànjànkàn

  • Enoch Adeboye – olórí gbogbo ijọ, Redeemed Christian Church of God
  • Chief Dr. Oyin Adejobi- òsèrékùrin, gbajugbaja akéwì
  • Gbenga Adeboye – olórin, aderinposonu ati
  • Toyin Adegbola- òṣèrébìnrin
  • Sheikh Abu-Abdullah Adelabu – onímọ̀ ati Aafa.
  • Isiaka Adeleke – olóṣèlú ati gómìnà tẹ́lẹ̀rí
  • Chief Adebisi Akande- gomina ìpínlẹ̀ Ọṣun tẹ́lẹ̀rí
  • General Ipoola Alani Akinrinade (RTD) - former Chief of Army Staff and the First Chief of Defence Staff ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
  • Akinloye Akinyemi – former Nigerian major
  • Bolaji Amusan - òsèrékùrin
  • Olusola Amusan – Olùdásílẹ̀, speaker
  • Ogbeni Rauf Aregbesola – gomina ìpínlẹ̀ Ọṣun tẹ́lẹ̀rí
  • Lanre Buraimoh - akọrin
  • Davido – Akọrin
  • Patricia Etteh, olóṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà ati obinrin àkọ́kọ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin
  • Daddy Freeze- oluseto orí afẹ́fẹ́
  • Bola Ige SAN-(1930–2001) olóṣèlú ati agbẹ́jọ́rò
  • W.F. Kumuyi – olórí gbogbo ijọ, Deeper Life Christian Church
  • Duro Ladipo – òsèrékùrin ati olukowe eré orí ìtàgé
  • Gabriel Oladele Olutola - Ààrẹ Apostolic church of Nigeria and LAWNA Territorial Chairman.
  • Iyiola Omisore – olóṣèlú ati engineer
  • Prince Olagunsoye Oyinlola – former Governor of Osun State and former Military Governor of Lagos State

Itokasi

Tags:

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ItanÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Ilé ẹ̀kọ́ gígaÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Ijọba Ìbílẹ̀Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Àwọn èèyàn jànkànjànkànÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ItokasiÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunAdaAwon Ipinle NaijiriaEde, NigeriaGboyega OyetolaIfetedoIjebu-JesaIla, NigeriaIle-IfeIlesaIpetumoduIpinle EkitiIpinle KwaraIpinle OgunIpinle OndoIpinle OyoIwo, NigeriaNàìjíríàObafemi Awolowo UniversityOtan AyegbajuStates of NigeriaÌrágbìjíÒṣogbo

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Masẹdóníà ÀríwáHarry BelafonteÀwọn FilipínòEsperantoEarthGeneral Exchange FormatJohn Lewis27 SeptemberIfá7 MayLinuxAdeniran OgunsanyaLítíréso alohunFederico de Roncali, 1st Count of AlcoyRahama SadauIfẹ̀Fidel Castro2023Glenn T. SeaborgMarcia Gay HardenAdo EkitiÀtòjọ àwọn òrìṣà YorùbáSpéìnIlẹ̀ YorùbáÀṣà YorùbáDirac (codec)Sam CookeÁìshà Bùhárí.rsCasimir BetelMichael Bamidele OtikoBukola SarakiInstagramJacqueline WolperTaiye SelasiUmaru Musa Yar'aduaTemilade OpeniyiAdama BarrowKọ́lá AkínlàdéÀsìá ilẹ̀ Dẹ́nmárkìObafemi AwolowoÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Fòpin sí SARS1341 EdméeTom MboyaList of sovereign statesSístẹ́mù ajọfọ̀nàkò jẹ́ọ́gráfìÒrò àyálò YorùbáLíktẹ́nstáìnìAnna TatishviliGuinea-BissauDÌdíje Wimbledon 1999 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanShahnez BoushakiNelson MandelaIrakCharles de GaulleOduduwaMẹ́rkúríù (plánẹ̀tì)Eniola AjaoLítíréṣọ̀OsloCristina Fernández de KirchnerÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáHouse of GoldÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàInternet Relay ChatVictoria University of ManchesterDJ Xclusive🡆 More