Rauf Aregbesola A bí i ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1957.
Ó jẹ́ àgbà olósèlú ọmọ ilẹ̀ Yorùbá láti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun orílẹ̀-èdè Nàíjíríà. Wọ́n dìbò yàn-án gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ní ọdún 2010 títí ó fí fipò náà Sílẹ̀ ní ọdún 2018 lẹ́yìn tó lo sáà kejì rẹ̀ tán. Gboyega Oyetola ni Rauf Arẹ́gbẹ́ṣolá fa agbára Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lé lọ́wọ́ lẹ́yìn sáa rẹ̀ ní ọdún 2019, olórí orílẹ̀-èdè Muhammadu Buhari yàn-án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà alábòjútó ètò abẹ́lé (Minister for Interior) orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Rauf Aregbesola | |
---|---|
Gomina Ipinle Osun | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 27 November 2010 | |
Asíwájú | Olagunsoye Oyinlola |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kàrún 1957 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Action Congress of Nigeria |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Rauf Aregbesola, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.