Orin-Ìyìn Orílẹ̀-Èdè

Èyí ni orin tí orílẹ̀-ède kan máa ń kọ nígbà tí wọ́n bá ń ṣe ayẹyẹ.

Wọ́n máa ń kọ ọ́ tí olórí orílẹ̀-èdè mìíràn bá wá bẹ̀ wọ́n wò. Wọ́n máa ń kọ ọ́ níbi tí àwọn ènìyàn bá pé jọ sí tàbí ibi òṣèlú tó bá ṣe pàtàkì. Ẹnìkan lè dá a kọ fún gbogbo ènìyàn tàbí kí gbogbo ènìyàn kópa nínu kíkọ rẹ̀.

Ọ̀rọ̀ inú orin yìí máa ń yin orílẹ̀-èdè àti àwọn ènìyàn tí ó wà nínú rẹ̀. Orin yìí máa n sábàá sọ àwọn ohun ribiribi tí ilẹ̀ kan ti gbé ṣe. Bouget de I’Isle ni ó kọ orin ti ilẹ̀ Faranse ní àsìkò ogun ní 1792. Francis Scott Key ni o kọ ti ilẹ̀ Àmẹ́rìkà ní 1814. A kò mọ ẹni tí ó kọ ‘God save the Queen’ ti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ṣùgbọ́n 1745 ni wọ́n kọ́kọ́ kọ ọ́. ‘Arise, O Compatriots’ ni ó bẹ̀rẹ̀ orin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a ń lò lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí.



Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

3 NovemberAṣọ ÀdìrẹỌdúnRoland BurrisÌyáMontana10 FebruaryAdekunle GoldÌṣesósíálístì2 MayRẹ̀mí ÀlùkòÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàNàìjíríàHypertext306 UnitasMaximilian SchellWọlé SóyinkáOlódùmarèVladimir PutinBD MimọMajid MichelLogicPópù Benedict 6kEmperor ShōmuQHypertext Transfer ProtocolWikipediaHilda Baci2010ArkansasAdunni AdeNebkaure AkhtoyỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀EyínRita DominicEre idarayaÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ ÅlandInstagramẸrankoISO 421720 OctoberEmperor MeijiAssouma UwizeyeMariam CoulibalyMinnesotaEsther OnyenezideÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáAlifabeeti OduduwaDEnglish languageÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáC++ISO 31-1Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sìAustrálíàSalvatore QuasimodoChristian BaleISO 150221016 Anitra30 AprilAlaskaJack LemmonNeanderthal🡆 More