Lech Walesa ( (ìrànwọ́·info); ojoibi 29 September 1943) je oloselu omo orile-ede Polandi, alakitiyan tele fun egbe irepo onisowo ati eto omo eniyan.
O gba Ebun Nobel fun iwa alafia ni 1983, o si je Aare ile Polandi lati 1990 titi di 1995.
Lech Wałęsa | |
---|---|
Aare ile Polandi | |
In office 22 December 1990 – 22 December 1995 | |
Alákóso Àgbà | Tadeusz Mazowiecki, Jan Krzysztof Bielecki, Jan Olszewski, Waldemar Pawlak, Hanna Suchocka, Józef Oleksy |
Asíwájú | Wojciech Jaruzelski (in country) Ryszard Kaczorowski (in exile) |
Arọ́pò | Aleksander Kwaśniewski |
1st Chairman of Solidarity | |
In office 1980 – 12 December 1990 | |
Asíwájú | N/A |
Arọ́pò | Marian Krzaklewski |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kẹ̀sán 1943 Popowo, Poland) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Solidarity |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Danuta Wałęsa |
Profession | Electrician |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Lech Wałęsa, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.