Jackie Chan (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 1954) jẹ́ òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò, ọ̀kọrin ọmọ orílẹ̀ èdè China..
Sinimá rẹ̀ máa ń dá lé ìjà afìpá àti gídígbò jà.
Jackie Chan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Can Gong saang 陳港生 Oṣù Kẹrin 7, 1954 Hong Kong, C.H.I |
Iṣẹ́ | Actor, director, screenwriter, producer, vintner |
Ìgbà iṣẹ́ | 1962 – present |
Olólùfẹ́ | Lin Feng-Jiao (1982 - present) |
Àwọn ọmọ | 2 |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Jackie Chan, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.