Adil (Adel) Abdul-Mahdi (al Muntafiki) (Lárúbáwá: عادل عبد المهدى ) (ojoibi 1942 ni Baghdad, Iraq) je Shi'a oloselu, onimo oro-okowo ati ikan ninu awon Igbakeji Aare ile Irak meji tele.
Teletele o ti je Alakoso Eto Inawo ninu ijoba igbadie.
Adil Abdul-Mahdi عادل عبد المهدي | |
---|---|
Adil Abdul-Mahdi in 2008 | |
Prime Minister of Iraq | |
In office 25 October 2018 – 7 May 2020 | |
Ààrẹ | Barham Salih |
Deputy | Thamir Ghadhban Fuad Hussein |
Asíwájú | Haider al-Abadi |
Arọ́pò | Mustafa Al-Kadhimi |
Minister of Oil | |
In office 8 September 2014 – 19 July 2016 | |
Alákóso Àgbà | Haider al-Abadi |
Asíwájú | Abdul Karim Luaibi |
Arọ́pò | Jabbar Alluaibi |
Vice President of Iraq | |
In office 7 April 2005 – 11 July 2011 Serving with Ghazi al-Yawer (until 2006) and Tariq al-Hashimi (after 2006) | |
Ààrẹ | Jalal Talabani |
Asíwájú | Rowsch Shaways |
Arọ́pò | Tariq al-Hashimi |
Minister of Finance | |
In office 2 June 2004 – 6 April 2005 | |
Alákóso Àgbà | Ayad Allawi |
Asíwájú | Kamel al-Kilani |
Arọ́pò | Ali Allawi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Adil Abdul-Mahdi al-Muntafiki 1 Oṣù Kínní 1942 Baghdad, Kingdom of Iraq |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent (since 2017) SIIC (1982–2017) Iraqi Communist (1970s) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Rajah |
Alma mater | University of Baghdad(BA) University of Poitiers (MA, PhD) |
Wọ́n bí Adil ní ìlú Baghdad ní ọdún 1942. Ó kẹ́kọ́ ní Baghdad College. Ó kẹ́kọ́ nípa ìmọ̀ Economics ní fasiti Baghdad. Adil ṣiṣẹ́ gẹgẹ bí akọ̀wé fun Iraqi foreign Ministry ni ọdún 1965. Ni ọdún 1972, o keko gboye Masters ni fasiti University of Poitiers.
Ni ojo kokandinlogbon, oṣù kọkànlá ọdún 2019, leyin ọpọlọpọ ifehonuhan, Mahdi sọpé ohun kowe fiposilẹ. Aṣòfin Iraqi fọwọ́sí ikowe fiposilẹ rẹ ni ọjọ́ kinni, oṣù Kejìlá ọdún, 2019.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Adil Abdul Mahdi, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.