Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn (Àdàkọ:Lang-sv) latowo Nobel Foundation, je ebun odoodun fun ipa pataki ninu ise iwosan.
O je ikan larin awon ebun Nobel marun ti Alfred Nobel dasile ni 1895 sinu ogun re, awon yioku je fun ipa pataki ninu Fisiksi, Kemistri, Litireso ati Alafia.
Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn Nobel Prize in Physiology or Medicine | |
---|---|
Bíbún fún | Ipa pàtàkì nínú Ìwòsàn |
Látọwọ́ | Royal Swedish Academy of Sciences |
Orílẹ̀-èdè | Sweden |
Bíbún láàkọ́kọ́ | 1901 |
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ | http://nobelprize.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.