Ìpínlẹ̀ Anambra: Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà

Ìpínlẹ̀ Anambra jẹ́ ìpínlẹ̀ kan láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè náà.

Wọ́n dá ìpínlẹ̀ náà lẹ̀ ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, ọdún 1991. Ìpínlẹ̀ Anambra sopọ Ìpínlẹ̀ Delta sí ìwọ̀-oòrùn, Ìpínlẹ̀ Imo sí gúúsù, Ìpínlẹ̀ Enugu sí ìlà-oòrùn ̀ti Ìpínlẹ̀ Kogi sí àríwá.

Anambra
Anambra State.
Anambra State.
Nickname(s): 
Location of Anambra in Nigeria
Location of Anambra in Nigeria
CountryÌpínlẹ̀ Anambra: Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà Nigeria
Date created27 August 1991
CapitalAwka
Government
 • GovernorCharles Chukwuma Soludo (APGA)
Area
 • Total4,844 km2 (1,870 sq mi)
Area rank35 of 36
Population
 (2006 census)1
 • Total4,055,048
 • Rank10 of 36
 • Density840/km2 (2,200/sq mi)
GDP (PPP)
 • Year2007
 • Total$6.76 billion
 • Per capita$1,585
Time zoneUTC+01 (WAT)
ISO 3166 codeNG-AN
Websiteanambrastateng.org
^1 Preliminary results

Gẹ́gẹ́ bí àbájáde ètò-ìkànìyàn ọdún 2022 àwọn olugbe tí wọn tó mílíọ́nnù mẹ́sàn-án ni wọ́n gbé ní Ìpínlẹ̀ náà. Orukọ Ìpínlẹ̀ náà ni wọ́n ṣàwárí ní ọdún 1976 látara àáríngbùngbùn ìlà-oòrùn Ìpínlẹ̀ náà, wọ́n fún Ìpínlẹ̀ náà lórúkọ ní ìbámu pẹ̀lú Odò Omambala, odò tó ń sàn jákèjádò ìpínlẹ̀ náà. Anambra jẹ́ orúkọ àyálò ti Omambala. Olú-ìlú rẹ̀ ni Awka, ìlú tó ń gbòrò ní kíákíá tí èrò inú rẹ̀ ti lé si láti Ẹgbẹ̀rún-lọ́nà-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin sí mílíọ́nnù mẹ́fà láàárin ọdún 2006 sí 2020. Ìlú Onitsha, tí ó jẹ́ ibùdó ìlú nínú ìtàn láti ìgbà ìmúnisìn àwọn aláwọ̀-funfun, ṣì jẹ̀ ọ̀gangan ìṣòwò láàárin Ìpínlẹ̀ náà..

Orúkọ-ìnagijẹ rẹ̀ ni "Ìmọ́lẹ̀ orílẹ̀ èdè" "Light of the Nation", Ìpínlẹ̀ Anambra jẹ́ ìpínlẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ tí ó gbòòrò jùlọ ní ààyè tàbí agbègbè ní orílẹ̀ èdè, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wí pé ìdijú-jiyàn rẹ̀ wà pèlu Onitsha, agbègbè tí ó tóbi jùlọ tí ó sì pọ̀ ni èrò nínú ìgboro tí àwọn èèyàn inú rẹ̀ tó mílíọ́nnù mẹ́jọ-àbọ̀ ni wọ́n ti ṣàwárí gẹ́gẹ́ bí àbájáde Africapolis ti ọdún 2020 tí ó mú Onitsha jẹ́ ìgboro-ìlú ẹlẹ́kejì tí ó gbòòrò jùlọ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní iye àti ẹlẹ́ẹ̀kẹ́ta ní ilẹ̀-adúláwọ̀. Bakan naa gẹ́gẹ́ bí àbájáde àwọn Demographia ti ọdún 2019 ìgboro Onitsha ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàdọ́ta ìgboro-ìlú tí ó tóbi jùlọ lágbàáyé pẹlu èro mílíọ́nnù mẹ́jọ Anambra jé Ìpínlẹ̀ tí ó pọ̀ jùlọ, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ẹlẹ́ẹ̀kejì ní kíkéré ni agbègbè ni. Agbègbè tí a mọ̀ sí Ìpínlẹ̀ Anambra ti jẹ́ agbègbè tí ó lajú ókérétán láti bíi ẹlẹ́èkẹsàn ọgọ́rù-únn AD, pẹ̀lú ìlú àbáláyé Nri, ti olú-ìlú rè jẹ́ Igbo-Ukwutẹ́lẹ̀rí nínú ìtàn láàárin Ìpínlẹ̀ náà. Àwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ Anambra jé àwọnIgbo, pẹ̀lú èdè Igbo tí ó jẹ́ gẹ́gẹ́ bí èdè àjùmọ̀ lò jákèjádò ìpínlẹ̀ náà.


Itokasi

Tags:

Delta StateNàìjíríàen:Enugu Stateen:Imo Stateen:Kogi StateÀwọn Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

MóldófàIlẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì13 May10 DecemberGeneral Exchange FormatÈdè JapaníKievÒgún LákáayéBukola SarakiKọ̀mpútàTrentonSao Tome àti PrincipeAisha YesufuỌ̀mọ̀wé Shafi LawalÀwọn Erékùsù PitcairnÀtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn Lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàJoe FrazierLinuxGalileo GalileiPólándìShahnez BoushakiCristina Fernández de KirchnerSharjahLilian EsoroOrin-ìyìn Orílẹ̀-èdè Gúúsù ÁfríkàRiyadhẸ̀rúndún 1kNÀrokòList of countries by percentage of water area29 JulyRichard J. RobertsFRosalyn Sussman YalowManuel Murillo Toro27 SeptemberRadio Studio 54 NetworkNiameyUChika OduahYorùbáIdris KutigiOpen Amẹ́ríkà 2012 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanEugenio MontaleTransport Layer SecurityVespasianChris RockGeorge Maxwell RichardsDrakeJẹ́mánì NaziFatoumata CoulibalyParisiHerbert MacaulayISO 22000Iṣẹ́ Àgbẹ̀Fáwẹ̀lì YorùbáTèmítọ́pẹ́ ṢólàjàMasẹdóníà ÀríwáAïcha BoroỌjọ́bọ̀Ísráẹ́lìAdó-ÈkìtìTokunbo AbiruGbọ̀ngàn Òfurufú KennedyGeorgiaToyin Adewale-GabrielTina TurnerÀkójọ àwọn èdè iṣẹ́ọbaPhillip Allen Sharp🡆 More