Ápártáìdì (Geesi: /əˈpɑːrteɪd/; Àdàkọ:IPA-af, segregation; lit.
"aparthood") ni sistemu ijoba ìṣègbéraga àwọn òyìnbó to da lori iyasotooto eya ti awon oyinbo fi tipatipa fi sejoba ni orile-ede Guusu Afrika ati South West Africa (ti a mo si Namibia loni) lati odun 1948 titi di 1994 Apartaidi je ijoba tipatipa to da lori baasskap (tabi Ìṣègbéraga àwọn òyìnbó), to mu daju pe awon oyinbo, botile je pe iye won ko po, gaba le ori gbogbo eniyan ni orile-ede Guusu Afrika ninu oselu, awujo ati okowo. Gegebi sistemu awon oyinbo yi se to, awon oyinbo ni won gbudo siwaju ni gbogbo igba, awon omo ara Asia te le won, be sini awon alawodudu ara Afrika lo gbodo gbeyin. The economic legacy and social effects of apartheid continue to the present day.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ápártáìdì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.