Betty Acquah

Betty Acquah (tí wọ́n bí ní 20 March 1965) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ghana àti ayàwòrán aṣègbèfábo.

Ó máa ń lo ọ̀dà àti òróró fún àwọn àwòrán rẹ̀.

Ìbẹ̀rèpẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Cape Coast ní Ghana, ó sì lọ sí Wesley Girls' Senior High School àti Holy Child School. Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí Kwame Nkrumah University of Science and Technology, níbi tí ó ti gboyè master's degree nínú ìmọ̀ Visual Arts, tó sì sojú dé yíya àwòrán. Ní Japan, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣẹ́ ọnà ní Tokyo School of Art.

Iṣẹ́ rẹ̀

Acquah ti ń ṣiṣẹ́ fún ọdún méje ní yàrá àwọn àwòrán fún Center for National Culture ní ìlú Accra, ó sì ti ń ṣàfihàn àwọn iṣẹ́ rè ní Berj Art Gallery láti ọdún 2002 wọ 2005. Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Ghana Association of Visual Artists. Ní oṣù kẹfà ọdún 2019, ó sọ ọ́ di mímọ̀ nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan tí Newsday BBC ṣe fún un pé ó wu òun láti ṣi national art gallery kan sí ìlú Ghana.

Acquah ti ṣàfihàn àwọn iṣẹ́ rè ní Ghana, Nàìjíríà, United Kingdom, India, Germany, Spain, Japan àti United States of America.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Tèmítọ́pẹ́ ṢólàjàZainab BalogunIrakAnna TatishviliEugenio MontalePearl ThusiOmanẸ̀yà ara ìfọ̀Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ SòmálíàÀsìá ilẹ̀ Írẹ́lándìBahtTransport Layer SecurityTsadAta ṣọ̀mbọ̀Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Àṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáChelsea F.C.DJ XclusiveIngrid BergmanList of countries by percentage of water areaTope AlabiWolfgang Amadeus MozartÌpínlẹ̀ ÍmòGeorge Emil PaladeColumbus, OhioArgẹntínàDanladi Mohammed ZakariGbólóhùn YorùbáLuther VandrossMexicoBukola SarakiKọ́lá AkínlàdéE13 MayPresident of the United States of AmericaRadio Studio 54 NetworkÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ UkréìnAntonio GramsciTrentonWindows Media VideoBobriskyAndhra PradeshArabAderonke ApataEwì AyabaEmeka IkeÈdèe YorùbáJohn LewisẸ̀rúndún 1kAMV Maersk AndamanElédùmàrèÌpínlẹ̀ ÒgùnBEmiliano FigueroaÀkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ ÈkóSouth African randỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Howard Martin TeminÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáOdumegwu OjukwuÀtòjọ àwọn òrìṣà YorùbáOliver MuotoRichard PryorAdebukola OladipupoAsif Ali ZardariCaroline DanjumaJorge Pacheco ArecoIfẹ̀ṢàngóJoão Café Filho🡆 More