Ìbà Pọ́njú-Pọ́ntọ̀

Ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀, tí a mọ̀ láti ìṣẹ̀wá sí yẹ́lò jaki tàbí àjálù pupa, jẹ líle Àkóràn àrùn.

Ní ọ̀pọ̀ ìṣẹlẹ̀, lára aamì ni ibà, òtútù, àìle jẹun, èébì, iṣan dídùn pàápáà ní ẹhìn, àti orí fífọ́. Àwọn aamì sábà maa ń jẹyọ láàrín ọjọ́ márùn ùn. Àwọn ènìyàn kan láàrín ọjọ́ kan tí ara wọṅ ti ń dá, ìbà náà padà wá, inú dídùn maa ń wáyé, àti ẹ̀dọ̀ bíbàjẹ́ bẹ̀rẹ̀ èyí to ń fa àwọ̀ ara pípọ́n. Bí èyí bá wáyé, ewu ṣíṣẹ̀jẹ̀ àti àwọn ìṣoro kídìnrín maa ń pọ̀si.

Ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀
Ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀A TEM micrograph of the yellow fever virus (234,000X magnification)
Ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀A TEM micrograph of the yellow fever virus (234,000X magnification)
A TEM micrograph of the yellow fever virus (234,000X magnification)
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-10A95. A95.
ICD/CIM-9060 060
DiseasesDB14203
MedlinePlus001365

Òkunfà àti ìwádìí aisàn

Àkóràn arùn pọ́njú-pọ́ntọ̀ ni okùnfà arùn náà èyí tí gígéjẹ abo ẹfọn ń tànká. Ènìyàn nìkan ni o ńkó àrùn yíì, àwọn pírámétì míìràn, àti ọ̀pọ̀ ẹ̀ya ẹ̀fọn míìràn. Ní àwọn ìlú, àwọn ẹ̀fọ́n ẹ̀yà Aedesaegypti ni ó sábà maa ń tàn káàkiri. Àkóràn yíì ni Kokoro RNA ti gẹ́nùsì Flavivirus. Àrùn náà le ṣòro láti sọ yatọ̀ sí àwọn aisàn míìràn, pà́apáà nígbà ìpinlẹ̀ àkọkọ́ bẹ́rẹ̀. Láti jẹ́rì ipò afurasí, àyẹwò ìdánwò ẹ̀jẹ̀ pẹ̀lú polymerase chain reaction ní a nílò.

Ìdẹ́kun àti Ìtọjú àti Ìsọtẹ́lẹ̀

Ìdábòbò àti ìmọ̀ọ́ṣe àjẹsára lódì sí àrùn pọ́njú-pọ́ntọ̀ wà, àwọn orílẹ̀-èdè kan sì nílò àwọn àjẹsára fún àwọn arinrìn-ajò. Àwọn ìgbìyànjú míìràn láti dẹ́kun àkóràn ni láti dín pípọ̀si àwọn ẹ̀fọn aṣòkunfà kù. Ní àwọn àgbegbè tí ibà pọ́njú-pọ́ntọ̀ wọ́pọ̀si ti àjẹsára ó sì wọ́pọ̀, ìwádìí kíákíá tí àwọn ìṣẹlẹ̀ àti abẹ́rẹ́ àjẹsára tí ọ̀pọ̀ lára àwọn ará ìlú ni ó ṣe pàtàkì láti dẹ́kun àjàkálẹ̀ arùn. Nígbà tí ó bá tiní àkóràn, ìṣàkóso jẹ́ ti aláámì láìsi ìwọ̀n tí ó jáfáfá Kankan lòdì sí àkóràn náà. Lára àwọn tí ó ní àrùn líle, ikú maa ń wáyé lára àwọn ìdajì ènìyàn tí kògba ìtọjú.

Ìmọ̀ nípa àrùn àti ìtàn

Àrùn pọ́njú-pọ́ntọ̀ ń ṣòkunfà àkoràn 200,000 àti ikú 30,000 lọ́dọọdún, pẹ̀lú bíi ìdá 90% ìṣẹlẹ̀ ní Áfíríkà. Bíi bílíọ́nù ènìyàn ni o ń gbé ní agbègbè àgbayé níbi tí àrùn náà ti wọ́pọ̀. Ó wọ́pọ̀ ní ibi oorùn àwọn agbègbè Gúúsù Amẹ́ríkà àti Áfíríkà, ṣùgbọ́n kìíṣe ní Áṣíà. Láti ọdún àwọn 1980, àwọn nọ́ńbà ìṣẹlẹ̀ àrùn pọ́njú-pọ́ntọ̀ ń pọ̀si. Èyí ń wáyé nítorí àwọn ènìyàn díẹ̀ tí wọ́n ń fún ní àjẹsára, ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn tí o ń gbé ní ìlú, àwọn ènìyàn tí o ńlọ káakiŕi, àti ìyípadà afẹ́fẹ́. Àrùn yíì bẹ̀rẹ̀ ní Áfíríkà, níbi tí o ti tàn dé Gúúsù Amẹ́ríkà nípasẹ̀ òwò ẹrú ní 17 century. Láti 17 century , ọ̀pọ̀ gbòógì àjàkálẹ̀ ti àrùn náà wáyé ní àwọn Amẹ́ríkà, Áfíríkà, àti Yúrópù. Ní àwọn 18 àti 19 century, ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀ ni wọ́n rí bíi èyí tí ó léwu jùlọ àrùn àkóràn. Kòkòrò ìbà pọ́njú-pọ́ntọ̀ ni kòkòrò ènìyàn àkọkọ́ tí a kọ́kọ́ ṣàwarí.

Ìtọ́kasí

Tags:

Ìbà Pọ́njú-Pọ́ntọ̀ Òkunfà àti ìwádìí aisànÌbà Pọ́njú-Pọ́ntọ̀ Ìdẹ́kun àti Ìtọjú àti Ìsọtẹ́lẹ̀Ìbà Pọ́njú-Pọ́ntọ̀ Ìmọ̀ nípa àrùn àti ìtànÌbà Pọ́njú-Pọ́ntọ̀ Ìtọ́kasíÌbà Pọ́njú-Pọ́ntọ̀IbàÈébì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Global Positioning SystemIPv6Òrò àyálò YorùbáÈṣùOpeyemi AyeolaÀjẹsára Bacillus Calmette–GuérinHugo ChávezLinda IkejiAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéSARS-CoV-2PakístànUrszula RadwańskaKetia MbeluISBNDomain Name SystemDapo AbiodunOperating SystemTÀmìọ̀rọ̀ QRGbólóhùn YorùbáSwídìnPópù SabinianAustrálíàWikipediaOlóṣèlúAderemi AdesojiOṣù Kínní 31R. KellyOlógbòIyàrá ÌdánáEhoroBenin30 MarchThomas CechOnome ebiFáwẹ̀lì YorùbáGoogleOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìOṣù Kínní 15New JerseyÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánAustríàJack LemmonZÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáÀwọn Òpó Márùún ÌmàleÒndó TownIlẹ̀ YorùbáÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáSeattleX67085 OppenheimerAIsiaka Adetunji AdelekeÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáEre idarayaWikimediaFísíksìÌran YorùbáAbdullahi Ibrahim GobirD. O. Fagunwa🡆 More