Yvonne Jegede

Yvonne Jegede jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, model àti adarí ètò lórí ẹrọ amóhù-máwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Jẹ́gẹ́dẹ́ di ìlú-mòọ́ká látàrí eré kan tí ó gbé jáde tí ó pè ní 3 is Company. Ó di ẹni ayé ń fẹ́ lẹ́yìn tí ó kópa nínú fọ́rán àwo orin African Queen tí gbajú-gbajà olótin 2Face Idibia àti Annie Macaulay gbé jáde.

Yvonne Jegede
[[file:
Yvonne Jegede
|frameless|alt=]]
Yvonne Jegede
Ilẹ̀abínibí Nàìjíríà

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

Wọ́n bí Yvonne Jẹ́gẹ́dẹ́ ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbòn oṣù Kẹ́jọ ọdún 1983 ní agbègbè Agenebode ní Ìpínlẹ̀ Edo, ní orílẹ̀-èdèNàìjíríà . Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ati girama ní Ìpínlẹ̀.Èkó, tí ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nílé ẹ̀kọ́ Yunifásitì Cyprus, nínú ìmọ̀ "International Relations".

Iṣẹ́ rẹ̀

Jegede bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré ní ọdún 2014 nibi tí ó ti kòpa nínú eré Missing Angels. Lẹ́yìn èyí, ó tún fara hàn nínú fọ́nrán àwo orin African Queen tí gbajúmọ̀ olórin 2Face Idibia tí wọ́n tún mọ̀ sí 2Baba gbé jáde ní ọdún 2005. Ó ti kó kópa nínú àwọn eré bíi: Okafor's Law, Single and Married, 10 Days in Sun City àti bẹ̀ẹ́ bẹ̀ẹ́ lọ. Ní ọdún 2015, ó gbé eré tirẹ̀ jáde tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní 3 is Company tí ó sì kópa nínú eré náà gẹ́gẹ́ bí olú-èdá ìtàn where she starred as the lead character.Ní ìparí ọdún 2016, ìwé ìròyìn ìgbàfẹ́ ti Genevieve Nnaji Yàtọ̀ sí eré ṣíṣe, Yvonne Jegede ó ti fara hàn nínú fọ́nrán àwo orin "Ego" tí olórin ilẹ̀ Nàìjíríà Djinee àti fọ́nrán àwo orin Kokose tí Sound Sultan gbé jáde.

Àwọn eré tí ó ti kópa

  • Missing Angels
  • Husbands of Lagos
  • 3 is Company
  • Okafor's Law
  • Pot of Life
  • Gold Statue
  • Side Chic Squad
  • Single and Married
  • 10 Days in Sun City
  • The Fight for the Family
  • The Silver Spoon
  • The Sassy One
  • Climax
  • Gone to America
  • Crazy Ex-Girlfriend
  • Forget Me Not
  • True Lies
  • Smiles of Sweet Love
  • Two Hearts That Binds Together
  • Strange Affection
  • Abike

Àwọn ìtọ́kasí

Àdàkọ:Authority control

Tags:

Yvonne Jegede Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀Yvonne Jegede Iṣẹ́ rẹ̀Yvonne Jegede Àwọn eré tí ó ti kópaYvonne Jegede Àwọn ìtọ́kasíYvonne JegedeNàìjíríà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Sístẹ́mù ajọfọ̀nàkò jẹ́ọ́gráfìQuetzalOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìOṣéáníàÍndíà3 MarchNicolaas Bloembergen22 AprilỌbàtáláÌṣúpọ̀ olùgbé.bvNISO 15022IndonésíàBetty AcquahHuniSekinat AdesanyaKirgistaniDigidesignTristan da Cunha.czReloaded (fíìmù ọdún 2009)Èdè XhosaLordiG2516 RomanÌtàn ilẹ̀ MálìẸ̀bùn Nobel nínú Ìṣiṣẹ́ògùnÀwọn ará Jẹ́mánìẸtuMillicent AgboegbulemÈdè Tswánà(196297) 2003 FANicolás AlmagroOlódùmarèAmòfinErékùṣùDYorubaÒkétéDìgbòlugiItan Ijapa ati AjaKetia MbeluÈṣùGuadalupe VictoriaPataki oruko ninu ede YorubaLawrence AniniSocotraAdrienne KoutouanGírámà YorùbáMeghalayaNepalFunke AkindeleBangladẹ́shìÀtòjọ àwọn àjọ̀dúnUgandaÈdè Gẹ̀ẹ́sìTosin AdeloyeOwe YorubaMalaysiaEhoroÌránìHypertext(5449) 1992 US5🡆 More