Yunifásítì Ìlú Èkó: Yunifasiti gbogbogbo ni nigeria

Yunifásítì ìlú Èkó (University of Lagos tàbí UNILAG) jé fásitì ìjọba àpapò ni Naijiria tó bùdó si ilu Èkó.

Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ
University of Lagos students festival 15
Yunifásítì ìlú Èkó
University of Lagos
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ
MottoIn deed and in truth.
Established1962
TypePublic
PresidentProf Tolu Olukayode Odugbemi
LocationNàìjíríàLagos, Nigeria
CampusUrban
Websitewww.unilag.edu.ng
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ
Faculty of Science

Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó

A dá UNILAG silẹ ni ọdún 1962, ọdún méjì lẹ́yìn òmìnira Naijiria independence of Nigeria láti ọwó àwọn Britain. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì márùn-ún tí a dá lè ní orílè-èdè Nàìjíríà, tí a mò sí "first generation universities". Eni Njoku ni a yàn gẹ́gẹ́ bí alákòóso àkọ́kọ́ ní yunifásítì ní ọdún 1962, èyí tí ọ́ ṣe títí di ọdún 1965 tí a sì ni ipò pada pẹ̀lú Saburi Biobaku. síbẹ̀síbẹ̀, nítorí àwọn àríyànjiyàn nípa bí a sè yàn sí ipò , ọ̀gbẹ́ni Kayode Adams gún Saburi pa , akẹ́kọ̀ọ́ tí ó gbàgbọ́ pé ááyan Saburi nítorí ẹyà ti ọ sí bójú mu.

Láti ọdún 2017 Títí di ojo òní , igbakeji olórí ni ọ̀jọ̀gbọ́n Oluwatoyin Ogundipe.ni ọdún 2019, Telifísàn BBC sọ̀rọ̀ nípa "female reporters were sexually harassed, propositioned and put under pressure by senior lecturers at the institutions – all the while wearing secret cameras". yíyọ àwọn obìrin oníròyìn lẹ́nu lórí ìbálópọ̀ àti ìfúgunmọ́ láti ọwọ́ àwọn olùkọ́ àgbà ní yunifásítì ní àwọn ilé-ìwé - láti ìgbà yìí wa ni wọ́n gbé kámẹ́rà pamọ́ sára.

Yunifásítì tí gbé oríṣiríṣi ọ̀jọ̀gbọ́n tí ó yanrantí jáde nínú ìmọ̀ síyẹ́ǹsì, òṣèlú, amòfin, àwọn oníṣòwò ńlá , òǹkọ̀wé, àwọn eléré ìdárayá, àwọn ọba, ìmọ̀-ẹ̀rọ,ti ìlú Nàìjíríà àwọn olóye gbogbo , àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwe mìíràn pẹ̀lú . Ni oṣù kẹsàn-án ọdún 2020, ọ̀kan lára àwọn nobel laureate àti ọ̀kan lára Pulitzer prize laureate ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí i ọmọ ilẹ́ ìwé yunifásítì ìlú Èkó , ọmọ ilẹ́ ìwé, olùkọ́, tàbí òṣìṣẹ́.

Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
Faculty of Science, University of Lagos
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
University of Lagos Lagoon front view from Seaside cottage theatre, Bariga
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
Lagoon Front Silhouette
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
View of the Third Mainland Bridge From the Lagoon Front
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
Green Space in University of Lagos

Ìran

Láti jẹ ile ẹkọ tó Dára jù lọ nínú títà yo imo, ìwà ati rí ran àwon eniyan lowo.

Iṣẹ

Láti ṣe ibùgbé tí ó dára fún ẹ̀kó, ìwé kika, Ìwádìí àti ìdàgbàsókè, níbití òṣìṣẹ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ yóò ní Àjosepò tó dán mọ́rán láti kojú ẹlẹ́gbẹ́ won ni gbogbo àgbáyé

Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
Faculty of Science, University of Lagos
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
University of Lagos Lagoon front view from Seaside cottage theatre, Bariga
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
Lagoon Front Silhouette
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
View of the Third Mainland Bridge From the Lagoon Front
Yunifásítì Ìlú Èkó: Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó, Ìran, Iṣẹ 
Green Space in University of Lagos

Ile kíkọ ati Arabara

Tags:

Yunifásítì Ìlú Èkó Ìtàn yunifásítì ìlú ÈkóYunifásítì Ìlú Èkó ÌranYunifásítì Ìlú Èkó IṣẹYunifásítì Ìlú Èkó Ile kíkọ ati ArabaraYunifásítì Ìlú ÈkóNaijiriaÈkó

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

LinuxÀwọn ọmọ PólàndìMarcia Gay Harden7 MayWestern Roman EmpireGeorge WeahÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ UkréìnỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)David MarkFlag of AzerbaijanMichael Bamidele OtikoHiggs bosonAdvanced Systems FormatÈdè Gẹ̀ẹ́sìOliver MuotoDJ XclusiveÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáLuther VandrossTobi BakreRemi AdedejiMinnaWiki CommonsAṣọDrakeKepu FerdeOlóṣèlúKady TraoréISO 5964Jacqueline WolperSátúrnù29 OctoberOhioIrelandRPakístànOjúewé Àkọ́kọ́David BaltimoreLítíréṣọ̀List of countries by percentage of water areaGúúsù ÁfríkàÌmúrìnDQGbÉmile DurkheimList of largest empiresÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFranklin PierceAsif Ali Zardari26 DecemberList of countriesUniversidade do Estado de Minas GeraisNelson MandelaJúpítérìÀtọ̀sí ajáNaijiriaCasinoYÌpínlẹ̀ ÁbíáTina TurnerÒfin Mẹ́wàáIfeanyi KaluL🡆 More