Paul Krugman

Paul Robin Krugman (pípè /ˈkruːɡmən/; ojoibi February 28, 1953) je onimo ikowo, alayokakiko ati olukowe omo orile-ede Amerika.

O je Ojogbon Oro Okowo ati Ikariaye ni Woodrow Wilson School of Public and International Affairs, Yunifasity Princeton, Ojogbon Centenary ni London School of Economics, ati akoro olootu fun The New York Times. Ni 2008, Krugman gba Ebun Iseranti Nobel ninu Oro-okowo fun afikun re si Ero Idunaduna Tuntun ati Jeografi Oro-Okowo Tuntun. Iwe-iroyin igbadegba Prospect Magazine diboyan gege bi omowe eni ekefa larin awon 100 tolewaju lagbaye ni 2005.

Paul Krugman
New Keynesian economics
Paul Krugman
Paul Krugman (2008)
NationalityAmerican
InstitutionPrinceton University
FieldInternational economics, Macroeconomics
Alma materMIT (Ph.D.)
Yale University (B.A.)
OpposedFreshwater economics
InfluencesJohn Maynard Keynes
Jagdish Bhagwati
Rudi Dornbusch
James Tobin
Avinash Dixit
Joseph Stiglitz
InfluencedMarc Melitz
ContributionsInternational Trade Theory
New Trade Theory
New Economic Geography
AwardsJohn Bates Clark Medal (1991)
Nobel Memorial Prize in Economics (2008)
Information at IDEAS/RePEc



Itokasi

Tags:

London School of EconomicsNobel Memorial Prize in EconomicsPrinceton UniversityThe New York TimesUSA

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

27 NovemberKárbọ̀nùLionel BarrymoreOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàSukarnoBoris YeltsinOrílẹ̀-èdèKọ̀mpútàFránsìÀwọn BàhámàRené DescartesEarthHTMLEhoroSQLOhun ìgboroBÌran YorùbáIdahoEre idarayaIfáÈdè ÍtálìÀlọ́8 OctoberÀwọn Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàQ22 AprilISO 3166-1Qasem SoleimaniPoloniumWerner FaymannOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Àṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáMuscatSílíkọ́nùSaint PetersburgBẹ̀lárùs1633 ChimayDiphalliaAlfonso García RoblesDorcas Coker-Appiah.geÁljẹ́brà onígbọrọ(7123) 1989 TT1.egÒrìṣà EgúngúnFilipínìFrederick LugardNecmettin ErbakanZincỌdún EgúngúnPópù Innocent 5kArewa 24Àrún èrànkòrónà ọdún 2019Joana FosterÌpínlẹ̀ Òndó.cmChristopher ColumbusISO 8601.aqIléỌ́ksíjìn🡆 More