Patrick Seubo Koshoni: Olóṣèlú

Patrick Seubo Koshoni tàbí Patrick Sẹ́húbò Koshoni tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1943 tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 2020 (April 17, 1943- 25 January, 2020) jẹ́ ajagun-fẹ̀yntì orí omi Nigerian Navy Vice Admiral, ọ̀gágun yányán Chief of Naval Staff àti mínísítà-ana fún ìlera nígbà ìṣèjọba ológun Ààrẹ Muhammadu Buhari.

Nígbà ìṣèjọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà-ana fún ètò ìlera, ó gbìyànjú láti ṣe ìdásẹ̀lé ètò Máàdámidófò lórí ìlera láìsí owó sísan kalẹ̀

Àdàkọ:BLP sources
Chief of Naval Staff
In office
1986–1990
AsíwájúRear Adm. A. Aikhomu
Arọ́pòVice Adm. M. Nyako
Federal Minister of Employment, Labour and Productivity
In office
1985–1986
Federal Minister of Health
In office
December 1983 – August 1985
AsíwájúD.C Ugwu
Arọ́pòOlikoye Ransome-Kuti
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1943-04-17)Oṣù Kẹrin 17, 1943
Lagos
AláìsíJanuary 25, 2020(2020-01-25) (ọmọ ọdún 76)
Alma materSt Finbarr's College
National Defence Academy
Military service
AllegiancePatrick Seubo Koshoni: Olóṣèlú Nigeria
Branch/servicePatrick Seubo Koshoni: Olóṣèlú Nigerian Navy
Years of service1962-1990
RankVice Admiral

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Muhammadu BuhariMáàdámidófòNigerian Navy

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Lítíréṣọ̀Oṣù Kínní 7Wolfgang Amadeus MozartBob BarkerKady TraoréKMargaret RutherfordÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáWKọ̀mpútàÀgùàlàSístẹ́mù ajọfọ̀nàkò jẹ́ọ́gráfìCelâl BayarÌmúrìnDJ XclusiveIke EkweremaduRabilu MusaAtiku AbubakarPAhmed Abdallah Mohamed SambiJ. Michael BishopJúpítérìSikiru Ayinde BarristerRiyadhJay-ZÈdè PọtogíGregory AgboneniÒfin Mẹ́wàáRọ́síàIfeanyi KaluPlùtòIlẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháìOsloA trip to jamaica3 Oṣù KejìláMarcia Gay HardenLagos State Fire ServiceCBitcoinGuineaÌwéìròyìnAláṣẹ Ìjọba Orílẹ̀-èdè PalẹstínìChelsea F.C.IrelandÌgèIpinle BenueFunke Adesiyan30 MayEre idarayaÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáSharjahFranceMSevero OchoaTẹlifísànWindows Media AudioEconomicsLuis Carrero BlancoJean Baptiste Gay, vicomte de MartignacMáàdámidófò2023John HowardÀtòjọ àwọn ilé iṣẹ́ Asọ̀rọ̀-mágbèsì ilẹ̀ NàìjíríàMársìRichard J. Roberts🡆 More