Jide Kosoko: Òṣéré orí ìtàgé

Ọmọba Jídé Kòsọ́kọ́ jẹ́ ògbónta òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.

Jide Kosoko: Ìgbà èwé àti ìrínàjò iṣẹ́ rẹ̀., Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀, Àwọn eré tí ó ti ṣe

Ìgbà èwé àti ìrínàjò iṣẹ́ rẹ̀.

Wọ́n bíi ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kínín Ọdún 1954 ní ìlú èkó sí ìdílé ọlọ́ba Kosoko ti erékùṣù èkó. Ó kàwé nípa okùn-òwò ní Yaba College of Technology. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe bí ọmọdé òṣèré ní ọdún 1964 ní eré Makanjuola tí wọ́n máa ṣàfihàn rẹ̀ ní amóhùnmáwòran. Ó ti kópa nínú oríṣiríṣi eré ti Nollywood ní èdè Yorùbá àti ní èdè gẹ̀ẹ́sì.


Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

Ó fẹ́ ìyàwó méjì; Karimat àti Henrietta pẹ̀lú àwọn ọmọ àti ọmọọmọ.

Àwọn eré tí ó ti ṣe

  • The Department (2015)
  • Gidi Up (2014) (TV Series)
  • Doctor Bello (2013)
  • The Meeting (2012)
  • Last Flight to Abuja (2012)
  • I'll Take My Chances (2011)
  • The Figurine (2009)
  • Jenifa

Àwọn ìtọ́kasí

Àwọn àjápọ̀ látìta

Tags:

Jide Kosoko Ìgbà èwé àti ìrínàjò iṣẹ́ rẹ̀.Jide Kosoko Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀Jide Kosoko Àwọn eré tí ó ti ṣeJide Kosoko Àwọn ìtọ́kasíJide Kosoko Àwọn àjápọ̀ látìtaJide KosokoNigeria

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

EminemMandy PatinkinAdeniran Ogunsanya2024Tony BlairÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàChlothar 1kFuel oil1 E11 m²Sebastián PiñeraAlain DelonISO 4ANSI escape codeRobin WilliamsỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Femi GbajabiamilaPanamaArgẹntínàÈṣùÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020Àgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn OlóróKàsínòKanayo O. KanayoPópù Alexander 6kMasẹdóníà ÀríwáÌsirò Statistiki2120 TyumeniaISO 14644-450 CentPennsylvaniaMicrosoftỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Nẹ́dálándìKosovoMargaret ThatcherBoolu-afesegbaÀrún èrànkòrónà ọdún 2019ISO 31-7TurkeyẸ́gíptì Ayéijọ́unQueen (ẹgbẹ́ olórin)Snoop DoggSkopjeList of sovereign statesJakartaISBNAustrálíàSheik Muyideen Àjàní BelloSlovakiaÒkun ÍndíàÌjíptìZagrebBimbo AdemoyeISO 3103United Arab EmiratesWikipẹ́díà l'édè YorùbáJúpítérìCalifornia29 JanuaryBẹ̀rmúdàISO/IEC 27005ISO 428PonnaCapital city🡆 More