Iṣan

Iṣan ni okùn ara tí ó rọ̀ jùlọ tí a lè rí ní ara púpọ̀ nínú ẹranko.

Nínú iṣan kọ̀ọ̀kan ni a ti rí protein, actin àtimyosin tí wọ́n gba orín ara wọn kọjá nínú iṣan lọ́hùn ún, àwọn èròjà wọ̀nyí ni wọ́n ń jẹ́ kí iṣan le, rọ̀ tábí kí ó wà láàrin méjì gẹ́gẹ́ bí ipò tí ara bá wà lásìkò kan.

Iṣan
Iṣan
A top-down view of skeletal muscle
Details
SystemMusculoskeletal system
Identifiers
Latinmusculus
TAA04.0.00.000
FMA5022 30316, 5022
Anatomical terminology

Iṣẹ́ iṣan

Láamra iṣẹ́ àwọn iṣan inù ara ni kí ó ràn wá lọ́wọ́ láti lè rìn, gbéra tàbí lọ láti ibìkan sí ibòmíràn lásìkò kan. Iṣan ló ma ń ṣiṣẹ́ ìbójútó ipò ara níbi ìdúró, ìbẹ̀rẹ̀, ìjókòó àti nínà sílẹ̀ gbalaja, tàbí nígbà tí a bá sùn sílẹ̀, iṣan ni ó ń ṣàkóso ìgbòkègbodò àti lílọ bíbọ̀ ara. Ó tún má ń jẹ́ kí àwọn bí ẹ̀jẹ̀ àti omi ó ríbi gbà káàkiri inú ara. Skeletal muscles in turn can be divided into fast and slow twitch fibers.

Àwọn Ìtọ́ka sí

Tags:

Iṣan Iṣẹ́ iṣanIṣan Àwọn Ìtọ́ka síIṣan

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Garba DubaMajid MichelKòkòròMinskArkansasÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáỌjọ́ ÀìkúAnatole FranceTajikistanLítíréṣọ̀H. H. AsquithDick Cheney28 SeptemberAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BindawaGúúsù-Ìlàòrùn ÁsíàÌnáwóOffice Open XML12 February(225273) 2128 P-LOlódùmarèMarie LuvLáọ̀sUSAÀsìá Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ MakẹdóníàSingapore10 FebruaryWasiu Alabi Pasuma.nl202222 DecemberOsmiumSheik Adam Abdullah Al-IloryÈdè YorùbáOṣù KọkànláSikiru Ayinde BarristerOṣù KejeNadia Fares AnlikerÈbuEhoroNgozi OparaNiger (country)Winston ChurchillTVladimir PutinGboyega Oyetola21 AugustAdenike OlawuyiỌjọ́ Àbámẹ́taÌṣíròỌjọ́ àwọn ỌmọdéYorùbáGrover ClevelandLeadSune BergströmUniform Resource LocatorISO 15022Ìpínlẹ̀ ÈkóHermann HessePópù Gregory 10kGbolahan MudasiruOgunRichard Mofe DamijoIléCheryl Chase (activist)1 August🡆 More