Halojín

Àwọn halojín (tabi ẹ́límẹ́ntì halojín) ni egbe kan lori tabili idasiko awon elimenti to ni awon elimenti marun ti won fi kemika ba ara won tan, fluorínì (F), klorínì (Cl), brómìnì (Br), iodínì (I), àti astanínì (At).

Elimenti 117 to je afowoda (ununseptium) na se e se ko je halojin. Ninu ifunloruko odeoni ti IUPAC, oruko egbe yi ni ẹgbẹ́ 17 (group 17) (tẹ́lẹ̀ bi: VII, VIIA, VIIB).

Halojín
Nonmetals in the periodic system
  Noble gases
  Halogens
  Other nonmetals
Apart from hydrogen metallloids are not placed in the p-block.

Egbe awon halojin nikan ni egbe ori tabili idasiko awon elimenti to ni awon elimenti ti won wa ni awon aye iwasi elo ti a mo meteeta ni igbonasi ati ifunpa onideede.



Itokasi


Tags:

AstatineBromineChemical elementFluorínìIodineKlorínìPeriodic tableUnunseptium

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

(5813) 1988 VLỌdúnOrin apalaPorto NovoZheng He3 MayÀtòjọ àwọn àjọ̀dúnSheik Adam Abdullah Al-IloryÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáInternet Movie DatabasePornhubBangladẹ́shìGírámà YorùbáSCondoleezza RicePópù Agapetus 2kMichael JordanNaijiriaLátfíàBaruch SpinozaOṣù Kínní12 AprilÌjímèrèÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nọ́rwèyYttriumChinedu IkediezeLouisianaOmoni OboliBerneÀkúrẹ́Olaitan IbrahimJulius AghahowaGeorge Clinton (Igbákejì Ààrẹ)Lẹ́tà gbẹ̀fẹ̀USARheniumOperating SystemRial Omani21 August21 OctoberBomadi23 DecemberBrie LarsonMichiganHọ́ng Kọng2022Nikita KhrushchevIbadan Peoples Party (IPP)C++1168 BrandiaEve MayfairÌmúrìnVladimir LeninAyo Adesanya16 AugustKìrúndìParáEmperor MeijiOrílẹ̀-èdèOṣù KọkànláỌjọ́ Àbámẹ́taISO 639-1Iṣẹ́ Àgbẹ̀HimalayaRalph Bunche🡆 More