Fèrèsé

Fèrèsé jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà Ilé tí ó ma ń wà ní àárín ògiri méjì ilé.

Ósì tún lè jẹ́ gíláàsì tí a fi sí ara ọkọ̀ láti lè jẹ́ kí òye, ohùn, tàbí afẹ́rẹ́ ó wọlé.

Ìyátọ́ fèrèsé ayé òde òní àti ayé àtijọ́

Láyé àtijọ́, ọ̀pọ̀ àwọn fèrèsé ló ma ń jẹ́ Pákó tí a figi ṣe, pàá pàá jùlọ ilé tí àwọn aláìní ma ń gbé ni wọ́n ma ń fi páànù àlòkù ṣe fèrèsé tàbí lẹ̀kùn. Ṣùgbọ́n láyé òde òní, àwọn gíláàsì tí ó ń dán gbinrin ni wón ma ń lò láti fi ṣe fèrèsé.

Ìwúlò Fèrèsé

Fèrèsé wù lò láti jẹ́ kí afẹ́fẹ́ ó wọlé yálà nígbà oru, ó sì yan ma ń jẹ́ kí a sa fún òtútù lásìkò òjò, ọyẹ́, àti ọgìnìntì

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Tẹ́lískópùIlé-Ifẹ̀NàìjíríàHesseIṣẹ́ Àgbẹ̀Pópù Adeodatus 2kDiamond JacksonEré ÒṣùpáOlusegun Olutoyin AgangaÈdè IjọỌ̀rúnmìlàSlofákíàTẹ́nìsKòréà Àríwá3254 BusOjúewé Àkọ́kọ́Sunita WilliamsAdrien BrodySaxonyLadi KwaliEre idarayaÍsótòpùJoana FosterBama, Nàìjíríà27 JuneOwe YorubaAfeez OwóRené DescartesBùrúndì22 OctoberCopenhagenAgbonGoogleRichard NixonVieno Johannes Sukselainen(7123) 1989 TT1LèsóthòÀsìá ilẹ̀ KánádàSimidele AdeagboṢàngó.guMayotte17 MarchISO 3166SukarnoQYukréìn.soHilary SwankHawaiiOhun ìgboro14 NovemberRihannaXJennifer LopezWikisourceTop-level domainÀwọn BàhámàArewa 24Gbólóhùn Yorùbá29 AprilÀdìjọ ìtanná25 JulyMavin RecordsÌbálòpọ̀🡆 More