Cleopatra Koheirwe

Cleopatra Koheirwe jẹ́ òṣèré, olórin àti akọ̀wé lórílẹ̀-èdè Uganda.

Ó kópa nínú eré The Last King of Scotland gẹ́gẹ́bí Joy ní ọdún 2006. Ó kópa nínú eré Sense8 lóri Netflix.. Ó ko ipa Ebony nínú eré Reflections èyí tí Nana Kagga ṣe adarí rẹ̀. Ó darapọ̀ mọ́ StarTimes Uganda ní oṣù kẹfà ọdún 2019 bí ìkan lára àwọn adarí wọn.

Cleopatra Koheirwe
Born15 Oṣù Kínní 1982 (1982-01-15) (ọmọ ọdún 42)
ShowMid-Morning Magazine
Station(s)Radiocity 97Fm
Time slot10am – 3pm
StyleMusic, celebrity gossip, news
CountryUganda
Orílẹ̀-èdèUgandan
Ẹ̀kọ́
  • Makerere University
  • University of South Africa (UNISA)
Iṣẹ́
  • Actress
  • Radio host
  • Writer
Ìgbà iṣẹ́1999–present
Àwọn ọmọ1

Iṣẹ́

Ní ọdún 2001, ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ oníjó àti olórin Obsession, ó sì wá níbẹ̀ títí di oṣù kẹta ọdún 2007. Ní ọdún 2010, ó kọ orin Ngamba. Cleopatra bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí agbóhùnsáfẹ́fẹ́ pẹ̀lú 91.3 Capital Fm níbi tí ó tí ṣe atọ́kun ètò Drive Time Show. Ní ọdún 2013, ó ṣe atọ́kun ètò fún U-Request show pẹ̀lú Radiocity 97Fm. Ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2013, òun àti Flavia Tumusiimr àti Juliana Kanyomozi ṣe adájọ́ fún ìdíje orin ti Tusker Project Fame ní Kampala. Cleopatra tí kópa nínú orísìírísìí eré bíi State Research Bureau, Sense8, Changes, Be the judge ài Yogera. Ní ọdún 2012, Reach a Hand mu láti sọ̀rọ̀ fún àwọn ọ̀dọ́ ni àwọn ilé ẹ̀kọ́. Ní ọdún 2010, nígbà tí wọ́n fẹ́ gbé eré Changes apá kejì kalẹ̀, òun àti Nick Mutuma, Pierra Makena, Níní Wacera àti Patricia Kihoro lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Rob Mellor Studios ní Atlanta láti kẹ́kọ̀ọ́ eré ṣíṣe dáadáa.

Ìgbésí ayé rẹ̀

Wọ́n bí Cleopatra sí ìdílé Jocelyn Twinesanyu àti Anthony Abamwikirize ní ọdún 1982. Ó bí ọmọ bìnrin ní ọjọ́ kẹjìlélógún oṣù kìíní ọdún 2014 fún ọkọ rẹ̀ Lwanda Jawar.

Àṣàyàn eré rẹ̀

2019 Kyaddala Rahu Counselor A Reach a Hand Uganda and Emmanuel Ikubese Films production on NBS
2018 #Family Leah Nabwiso Films TV series.
Mela Naava Katende Savannah MOON Web Series
27 Guns Alice Kaboyo Natasha Museveni Directed film
2017 Reflections Ebony Upcoming TV series created and directed by Nana Kagga Macpherson
2016 Sense8 Mother TV series created & directed by The Wachowskis
2013 Kona Jakki Kenyan telenovela
2011 State Research Bureau Faith Katushabe supporting role
Yogera Hope/ G double lead
2010 Be the Judge Lucy Mango a Kenyan local TV series
2008-10 Changes Nanziri Mayanja a Kenyan DSTV series in seasons 1 & 2 in a supporting role
2006 The Last King of Scotland Joy supporting role

Àmì ẹ̀yẹ

Year Award Category Esi
2013 RTV Awards Best Newcomer female radio presenter Yàán
2013 Nile Diaspora's International Film Festival (NDIFF) Outstanding Actress Honoree Award Gbàá
2013 Radio & Television Academy Awards (RTVAA) Uganda Best Late Afternoon Show-English (The Jam on Radiocity 97Fm) Gbàá
2013 Buzz Teeniez Awards Teeniez Role Model Yàán
2012 Super Talent Awards Most Gifted Actress Yàán
2012 Pearl International Film Festival Awards (PIFFA) Uganda Best Supporting Actress (S.R.B) Yàán
2011 Kalasha Film & Television Awards, Kenya Best Actress in a TV Drama (Be the Judge) Yàán

Àwọn Ìtọ́kàsi

Tags:

Cleopatra Koheirwe Iṣẹ́Cleopatra Koheirwe Ìgbésí ayé rẹ̀Cleopatra Koheirwe Àṣàyàn eré rẹ̀Cleopatra Koheirwe Àmì ẹ̀yẹCleopatra Koheirwe Àwọn Ìtọ́kàsiCleopatra Koheirwe

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ArgẹntínàMeghalayaÈdè GermanySocotraỌjọ́ AjéLatefa AhrarKárbọ̀nù.rsÒrò àyálò Yorùbá2458 VeniakaverinÌpínlẹ̀ BauchiGuadalupe VictoriaÌgbà DẹfoníàTẹ́lískópù Òfurufú HubbleAdeniran OgunsanyaOrílẹ̀-èdèOṣéáníà93 DaysInternational Organization for StandardizationBella DisuWikipẹ́díà l'édè YorùbáISO 216Èdè XhosaOmanTanganyikaMọ́ṣálásíD. O. FagunwaBarbra StreisandSaadatu Hassan LimanAmane BerisoVladimir LeninMichael HainischChristmasMàkáùEloy AlfaroNSeychellesBotswanaKikan Jesu mo igi agbelebuEfinrinPDF417Robert S. MullikenBerom languageFausat BalogunYinka AjayiÁrgọ̀nùTuedon MorganMariah CareyZulu SofolaÌwọ̀n Ẹyọ Akáríayé SIMain PageDenrele EdunBurundiC++Jean-Paul SartreÒkun MẹditéránìFáráòJuho Kusti Paasikivi🡆 More