27 IGuns jẹ ere iṣe, fiimu ìrìn-ajo nipa Yoweri Museveni ati awọn ẹlẹgbẹ ologun rẹ lakoko Ogun Inu Igbo Ugandan .Natasha Museven Karugirei jẹ oludari nipasẹ, ọmọbinrin Yoweri Museveni, o si ṣe afihan ni Kampala ni Oṣu Kẹsan ọjọ keejo, ọdun 2018 lẹhin igba na otun ṣe afihan ni Johannesburg South Africa ni Oṣu Kẹsan Ọjọ kankandilogun.
Ipa asiwaju ti Yoweri Kaguta Museveni ni a fun Arnold Mubangizi gẹgẹbi ipa akọkọ rẹ. Diana Museveni Kamuntu ṣe iya rẹ https://www.duhoctrungquoc.vn/wiki/en/Janet_Museveni" rel="mw:ExtLink" title="Janet Museveni" class="duhoc-yo cx-link" data-linkid="130">Janet Kataha Museni
Yiya 27 Guns bẹrẹ ni Oṣu Kẹjọ Ọjọ kejo, Ọdun 2017 o si tẹsiwaju fun ọjọ aadọrun. Ipolongo fiimu naa ti jade ni Osu kaaru odun 2018. A ya fiimu naa ni Mpigi/ Singo, Buikwe ati Kampala pẹlu awọn oṣere ati oṣiṣẹ ti o wa ni awọn aaye fun gbogbo iyaworan naa. Isaiah 60 Productions lose awọn iṣelọpọ ati pinpin fiimu na.
|url-status=
ignored (help)This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article 27 Guns, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.