Beyoncé Knowles

Beyoncé Giselle Knowles ( /biˈjɒnseɪ/ bee-YON-say; bíi Ọjọ́ kẹrin Oṣù kẹsán Odún 1981), tí wọ́n mọ̀ sí Beyoncé jẹ́ alágbe tí ó ń kọ R&B àti ẹlẹ́ṣọ́ aṣọ ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.

Wọ́n bíi ní Houston ní Texas, níbi tó ti lọ sí ilé ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ọnà síṣe. Knowles kọ́kọ́ gbajúmọ̀ ní òpin èwádún 1990 gẹ́gẹ́ bí asíwájú akọrin ẹgbẹ́ olórin R&B Destiny's Child, ìkan nínú àwọn ẹgbẹ́ olórin lóbìnrin tí ó tàjùlọ lágbáyé.

Beyoncé Knowles
Knowles in 2013
Knowles in 2013
Background information
Orúkọ àbísọBeyoncé Giselle Knowles
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹ̀sán 4, 1981 (1981-09-04) (ọmọ ọdún 42)
Ìbẹ̀rẹ̀Houston, Texas, United States
Irú orinR&B, pop, soul, hip hop
Occupation(s)Singer, songwriter, record producer, actress, dancer, entertainer, choreographer, model, video director
Years active1997–present
LabelsColumbia
Associated actsDestiny's Child, Jay-Z, Solange Knowles
Websitebeyonceonline.com
Beyoncé Knowles
Beyoncé's autograph

Àwọn orin

Àwọn àwò-orin

  • Dangerously In Love (2003)
  • B'Day (2006)
  • I Am... Sasha Fierce (2008)
  • 4 (2011)

Agbo

  • Live at Wembley (2004)
  • The Beyoncé Experience Live (2007)
  • I Am... Yours: An Intimate Performance at Wynn Las Vegas (2009)
  • I Am... World Tour (2010)
  • Live at Roseland (2011)

Àwọn àdákọ

  • Crazy In Love (ft. Jay-Z) (2003)
  • Baby Boy (ft. Sean Paul) (2003)
  • Me, Myself And I (2003)
  • Naughty Girl (2004)
  • Check On It (2005)
  • Déjà Vu (ft. Jay-Z) (2006)
  • Ring the Alarm (2006)
  • Irreplaceable (2006)
  • Beautiful Liar (2007)
  • Get Me Bodied (2007)
  • Green Light (2007)
  • If I Were a Boy (2008)
  • Single Ladies (2008)
  • Diva (2009)
  • Halo (2009)
  • Ego (2009)
  • Sweet Dreams (2009)
  • Broken-Hearted Girl (2009)
  • Video Phone (2009)
  • "Why Don't You Love Me" (2009)
  • Run the World (Girls) (2011)
  • Best Thing I Never Had (2011)
  • Countdown (2011)
  • Love On Top (2011)

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Beyoncé Knowles Àwọn orinBeyoncé Knowles Àwọn àdákọBeyoncé Knowles Àwọn ìtọ́kasíBeyoncé KnowlesDestiny's ChildHoustonen:Wikipedia:IPA for Englishen:Wikipedia:Pronunciation respelling key

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ajagun Ojúòfurufú NàìjíríàKòréà ÀríwáGuinea-Bissau22 AprilỌ̀rànmíyànWikimediaJames CagneyNọ́rwèyEhoroOperating SystemInternetÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáBarack ObamaIlẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnAbẹ́òkútaFrederick LugardÈdè PólándìOlódùmarè30 AprilDorcas Coker-AppiahRẹ̀mí ÀlùkòÒṣèlúIlẹ̀gẹ̀ẹ́sì24 OctoberRené DescartesMadagásíkàChristopher ColumbusUttar PradeshMandy PatinkinWaterÀmìọ̀rọ̀ QR8 OctoberOrúkọ YorùbáAloma Mariam MukhtarShehu Abdul RahmanMercedes-BenzỌrọ orúkọSantos AcostaRamesses XICharlize Theron10 October2 JuneSístẹ́mù ajọfọ̀nàkò jẹ́ọ́gráfìGeorge ReadJohn MiltonAbidjanPópù Jòhánù 14kMalaysiaÈdè ÍtálìNkiru OkosiemeRonald ColmanIlú-ọba Ọ̀yọ́Ingrid AndersenWikisourceRembrandtAlfonso García Robles.afNamibiaÀwọn Bàhámà.coJuliu Késárì🡆 More