Bangladẹ́shì

Bangladesh (ìrànwọ́·ìkéde) (Bengali: বাংলাদেশ, pronounced ; Bangladesh), fun ibise gege bi orile-ede Olominira Araalu ile Bangladesh (Bengali: গণপ্রজাতন্ত্রী বাংলাদেশ Gônoprojatontri Bangladesh) je orile-ede kan ni Guusu Asia.

O ni bode mo India ni gbogbo awon egbe re ayafi fun bode kekere mo Burma (Myanmar) ni guusuilaorun ati mo Ebado Bengal ni guusu. Lapapo mo ipinle West Bengal ni India, o je agbegbe eya-ede Bengal. Oruko Bangladesh tumosi "Orile-ede ile Bengal" ni ede ibise Bengal.

People's Republic of Bangladesh

গণপ্রজাতন্ত্রী বাংলাদেশ
Gônoprojatontri Bangladesh
Orin ìyìn: Amar Shonar Bangla



My Golden Bengal
Location of Bangladẹ́shì
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Dhaka
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaBangla
Orúkọ aráàlúBangladeshi
ÌjọbaParliamentary republic
• President
Zillur Rahman
• Prime Minister
Sheikh Hasina Wazed
• Speaker
Ad.Abdul Hamid
Independence 
• Declared
March 26, 1971
Ìtóbi
• Total
147,570 km2 (56,980 sq mi) (94th)
• Omi (%)
7.0
Alábùgbé
• 2009 estimate
162,221,000 (7th)
• Ìdìmọ́ra
1,099.3/km2 (2,847.2/sq mi) (5th)
GDP (PPP)2009 estimate
• Total
$226.205 billion (48th)
• Per capita
$1,398 (153rd)
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$84.196 billion (58th)
• Per capita
$690 (147th)
Gini (2000)33.4
medium
HDI (2007) 0.543
Error: Invalid HDI value · 146th
OwónínáTaka (BDT)
Ibi àkókòUTC+6 (BST)
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù880
Internet TLD.bd
  1. Adjusted population, p.4,

Awon bode Bangladesh lowolowo loni je didasile pelu ipinya Bengal ati India ni 1947, nigbati agbegbe na di egbe apailaorun orile-ede tuntun Pakistan. Sugbon, o pinsoto lati egbe apaiworun pelu 1,600 km (994 mi) ile India. Nitori idawaloto oloselu ati ede ati aisi okowo to fa isodi awon araalu si Iwoorun Pakistan, to fa ogun fun ilominira ni 1971 ati idasile orile-ede Bangladesh. Leyin ilominira orile-ede tuntun yi koju iyan, ajalu eda ati aini togbale, ati wahala oselu ati igbajoba ologun. Ipadade oseluaraalu ni 1991 mu itoro ati idagbasoke okowo wa.

Bangladesh ni orile-ede keje to lopo eniyan julo ati ikan ninu awon orile-ede to lopo eniyan kikijulo laye pelu osuwon aini giga. Sibesibe, GDP ti enikookan ti di emeji lati 1975, be sini osuwon aini ti re bi 20% lati ibere awon odun 1990. Bangladesh je ikan ninu awon orile-ede ti a npe ni okowo "Next Eleven". Dhaka, oluilu re, ati awon gbongan igboro ilu miran kopa ninu idagbasoke yi.

Fun jeografi, orile-ede yi gba ile olora Delta Ganges-Brahmaputra be sini oun ni omoyale lododun ojo monsoon ati iji birikiti. Bangladesh ni ile yepe eti-odo to gunjulo laye ni ti Cox's Bazaar. Oselu re ni oseluaralu ile-asofin. Bangladesh je ikan ninu Ajoni awon Orile-ede, OIC, SAARC, BIMSTEC, ati D-8. Gege bi Banki Agbaye se sakiyesi ninu Oro nisoki Orile-ede re ni July 2005, Bangladesh ti ni ilosiwa gidi ni idagbasoke eniyan ni apa imookomooka, idogba ako/abo ni ile-eko ati iresile ipoju awon eniyan. However, Bangladesh si nkoju awon isoro nla, ajakale iwaibaje awon oloselu ati osise ijoba, economic competition relative to the world, serious overpopulation, widespread poverty, and an increasing danger of hydrologic shocks brought on by ecological vulnerability to climate change.

National symbols of Bangla-Desh (Official)
State animal Bangladẹ́shì
State bird Bangladẹ́shì
State tree Bangladẹ́shì
State flower
State aquatic marine mammal Bangladẹ́shì
State reptile Bangladẹ́shì
State fruit Bangladẹ́shì
State fish Bangladẹ́shì
State mosque Bangladẹ́shì
State temple Bangladẹ́shì
State river Bangladẹ́shì
State mountain Bangladẹ́shì

Itan

Bangladẹ́shì 
Somapura Mahavihara in Paharpur, Bangladesh is the greatest Buddhist Vihara in the Indian Subcontinent, built by Dharmapala of Bengal.
Bangladẹ́shì 
Sixty Dome Mosque in Mosque city of Bagerhat was built in the 15th century and is the largest historical mosque in Bangladesh, as well as a World Heritage site.
Bangladẹ́shì 
The Shaheed Minar, which commemorates the Bengali Language Movement, is a well known landmark in Bangladesh.
Fáìlì:P015.gif
Sheikh Mujibur Rahman (3rd person from right), founder of Bangladesh and Maulana Bhashani (4th person from right) in 1953.

Awon iseku asaolaju ni agbegbe Bengal loseyin de egberun merin odun, nigbati ibe je titedo lowo awon Dravidian, Tibeto-Burman, ati awon Austro-Asiatic. Orisun oro Bangla" tabi "Bengal" ko je mimo, botilejepe won nigbagbo pe o wa lati Bang, eya to n sede Dravidian to budo si agbegbe yi larin odun 1000 kJ.


Awon Itokasi

Tags:

Bengali languageBn-বাংলাদেশ.ogaBurmaCountryFáìlì:Bn-বাংলাদেশ.ogaIndiaSouth AsiaWest Bengal

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

InternetÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Ìran YorùbáFile Transfer ProtocolNigerian People's PartyOperating SystemPópù Benedict 16kAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéIPópù LinusWeb browserTashkentJohn GurdonKọ̀mpútàMathimátíkìWolframu2024(213893) 2003 TN2Lẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Hugo ChávezLinda IkejiÌpínlẹ̀ ÈkìtìÌránìWikimediaBeirutLudwig van BeethovenPópù SabinianÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàOhun ìgboroJésùJakartaOlu FalaeEre idaraya(211536) 2003 RR11Ini Dima-OkojieIsaiah WashingtonÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáJack LemmonYunifásítì HarvardWalter MatthauRọ́síàWikisourceSíńtáàsì YorùbáGlobal Positioning SystemDiamond JacksonTeni (olórin)LebanonÒgbóniAdaptive Multi-Rate WidebandYul EdochieJohn LewisMegawati SukarnoputriNorman Manley2009ÀrokòMicrosoftXDomain Name SystemÌpínlẹ̀ ÒgùnC++OmiOlógbòVictoria University of ManchesterDapo AbiodunSaadatu Hassan LimanBarry WhiteThe New York TimesÈdè FínlándìOṣù Kẹta🡆 More