Bahrain tabi Ile-Oba BahrainNí ọdún 1995, àwọn ènìyàn tí ó ń gbé orílẹ̀-èdè yìí tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀ẹ́dégbẹ̀ta àti ààbọ̀ (555,000).
Èdè Lárúbááwá (Arabic) ni èdè ìjọba ní ibẹ̀. Àwọn èdè kan tún wà tí wọ́n ń sọ níbẹ̀. Àwọn èdè náà ni fáàsì (farsi) tí àwọn tí ó ń sọ ó ẹgbẹ̀rún méjìdínláàádọ́ta (48, 000); Úúdù (Urdu) tí àwọn tí ó ń sọ ọ́ tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000) àti àwọn èdè fílípíìnì (Phillipine) mìíràn tí àwọn tí ó ń sọ wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbayì ní ilẹ̀ yìí sí i gẹ́gẹ́ bí èdè òwò àti èdè ìṣe àbẹ̀wò sí ìlú (tourism).
Kingdom of Bahrain مملكة البحرين Mamlakat al-Baḥrayn | |
---|---|
Orin ìyìn: بحريننا Bahrainona Our Bahrain | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Manama |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Arabic |
Ẹ̀sìn | Islam (Sunni) |
Orúkọ aráàlú | Bahraini |
Ìjọba | Constitutional Monarchy |
• King | Hamad bin Isa Al Khalifah |
• Queen | Sabika bint Ibrahim |
• Prime Minister | Khalifah ibn Sulman Al Khalifah |
Independence | |
• From Portugal | 1602 |
• From Persia | 1783 |
• From United Kingdom | December 16, 1971 |
Ìtóbi | |
• Total | 750 km2 (290 sq mi) (184th) |
• Omi (%) | 0 |
Alábùgbé | |
• Estimate | 791,000 (159th) |
• Ìdìmọ́ra | 1,189.5/km2 (3,080.8/sq mi) (7th) |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $27.014 billion (118th) |
• Per capita | $34,662 (32nd) |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $21.236 billion (96th) |
• Per capita | $27,248 (3rd) |
HDI (2007) | ▲ 0.895 Error: Invalid HDI value · 39th |
Owóníná | Bahraini dinar (BHD) |
Ibi àkókò | UTC+3 |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 973 |
ISO 3166 code | BH |
Internet TLD | .bh |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Báháráìnì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.