Ogagun Agba Abd al-Rahman Mansur al-Hadi (Lárúbáwá: عبدالرحمن منصور الهادي; ojoibi 1945) je oloselu ara Yemen to je Igbakeji Aare ile Yemen lati 3 October 1994.
Won yansipo bi Adipo Aare ni 4 June 2011 nigba aisimi ara Yemen 2011, leyin ti Aare Ali Abdullah Saleh ti ni ipalara leyin idigbolu ile re pelu bombu. Saleh si ni Aare onibise ile Yemen.
Abd al-Rahman Mansur al-Hadi عبدالرحمن منصور الهادي | |
---|---|
Vice President of Yemen | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 3 October 1994 Acting President Since 4 June 2011 | |
Ààrẹ | Ali Abdullah Saleh |
Alákóso Àgbà | Muhammad Said al-Attar Abdul Aziz Abdul Ghani Faraj Said Bin Ghanem Abdul Karim al-Iryani Abdul Qadir Bajamal Ali Muhammad Mujawar |
Asíwájú | Ali Salim al-Beidh |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1945 Abyan, Aden Protectorate (now Yemen) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | General People's Congress |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Abd al-Rab Mansur al-Hadi, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.